07/16/2024
AWURE ISE GBIGBA TO YARA SISE KIAKIA
TO COLLECT BIG CONTRACT +2349014572744
- Ori Ijapa tutu tabi gbigbe kan
- Ose ganah tabi ose dudu
- Etu ibon gidi
- Imi ojo
* A o gun ori Ijapa yen papo mo imi ojo
* A o po mo Ose yen
* A o te ifa Ejiogbe sori ose na
* A o wa bu etu ibon si oju ibi ti a te Ejiogbe si lara ose yen.
* A o fi ina si, ti o ba ti jona
* A o wa po gbogbo re papo mo ose yen.
* A o wa pe gbolohun re si wipe:
GBOLOHUN RE
Iyokuyo lojo nyo (3x)
Igbakugba letu ngba (3x)
Iyokuyo lahon nyori (3x)
Iyokuyo ni ki ise nlanla ma yo si owo (hand) emi ---omo---lowo lati oni lo.
A o ma fi ose na we ni idaji kutukutu ojo Monday, Tuesday, Thursday.
Jowo ise yi wa fun awon contractors to ma n gba ise daadaa, tabi awon onise owo nla
IKILOPATAKI
tio bafe ki ise yii je fun o dada koko bami share ise yii si opolopo group kosi fi comment re se adura tio bawu o funmi nitori anfani elomi ni oro gbogbo yio di ayo ninu odun yii lase edumare
ENITI ISE YII BAWU LATI SE SUGBON TIKO SI AYE TABI TIKO MON BIO SEFESE KIO MESSAGE MI LORI WHATSAPP ((09014572744)) ALE RAN YIN LOWO LATI BAYIN SEAWURE ISE GBIGBA TO YARA SISE KIAKIA
TO COLLECT BIG CONTRACT +2349014572744
- Ori Ijapa tutu tabi gbigbe kan
- Ose ganah tabi ose dudu
- Etu ibon gidi
- Imi ojo
* A o gun ori Ijapa yen papo mo imi ojo
* A o po mo Ose yen
* A o te ifa Ejiogbe sori ose na
* A o wa bu etu ibon si oju ibi ti a te Ejiogbe si lara ose yen.
* A o fi ina si, ti o ba ti jona
* A o wa po gbogbo re papo mo ose yen.
* A o wa pe gbolohun re si wipe:
GBOLOHUN RE
Iyokuyo lojo nyo (3x)
Igbakugba letu ngba (3x)
Iyokuyo lahon nyori (3x)
Iyokuyo ni ki ise nlanla ma yo si owo (hand) emi ---omo---lowo lati oni lo.
A o ma fi ose na we ni idaji kutukutu ojo Monday, Tuesday, Thursday.
Jowo ise yi wa fun awon contractors to ma n gba ise daadaa, tabi awon onise owo nla
IKILOPATAKI
tio bafe ki ise yii je fun o dada koko bami share ise yii si opolopo group kosi fi comment re se adura tio bawu o funmi nitori anfani elomi ni oro gbogbo yio di ayo ninu odun yii lase edumare
ENITI ISE YII BAWU LATI SE SUGBON TIKO SI AYE TABI TIKO MON BIO SEFESE KIO MESSAGE MI LORI WHATSAPP ((09014572744)) ALE RAN YIN LOWO LATI BAYIN SE