23/12/2022
Oro pelu Ase Meje f'eni to gbagbo.👏👏👏🙏🙏🙏
Gbo Oro mejeeje na ati asotele fun aiye re.
1.Oro Akoko:Yio dara fun o l'opin Odun yi ju ero re lo!
2.Oro Keji:Oro re a dayo k'odun yi to pari!
3.Oro Keta:Aye o ni b'ojo ayo ati eye re je!
4.Oro Kerin:Ogo re a buyo!
5.Oro Karun:Eni ba robi si o leyi toku lodun yi yio f'ori ara re gbe e!
6.Oro Kefa:Ire gbogbo to ku ninu Odun yi yio je tire!
7.Oro Keje:Eni ba ro'ku ro o tabi gb'abode Iku nitori re tabi idile re,yio f'emi ara re di i l'oruko Jesu Kristi.Amin!,Asan wa S'ire Asan wa S'ayo.A ku ibere Isinmi Opin Ose.Alaafia!!!