Ijile oro lat'ori Ite _ Alore n ke

Ijile oro lat'ori Ite _ Alore n ke Ijile Oro kun fun awon oro ti o mu Itunu, Igbala, Isipaya, Ifokanbale ati beebee lo wa. ORO LATI ENU ALORE

01/10/2021

Oro Olorun dabi owe

Ipile ote ni a maa n mo
23/03/2020

Ipile ote ni a maa n mo

E je kase pele pele, ti Oluwa lase
15/12/2019

E je kase pele pele, ti Oluwa lase

28/07/2018

IJILE ORO 9.

Ko si iku ti yoo pa agba ti a koni i ba poolo ori re nibe.

Looto ni, sugbon eje ki a daaro daadaa, se poolo ori agba wulo fun agba mo?

14/05/2018

Ojumo Ire.

14/05/2018

ORO NI YOO SORA A RE!

23/10/2017

IJILE ORO.

8.
Lotito lo dara ki eniyan sa ipa re lati se aseyori lenu ise t'oba yan laayo sugbon, aseyori ti oba ti nilo lati re omonikeji je, tabi ree pale tabi ti o nilo lati se suta fun un ko dara rara, Olorun ko ni inu didun sii. Nitorinaa mo rowa eje ki a tepa mo'se owo wa ki asi maa be Olorun loore-koore. T'emi ati tiyin nitooto, Alore.
Ko nii soro se fun gbogbo wa lase Edumare. .... AMIN.

17/09/2017

PARI OWE YI:

Oti kii pani ki a ......................

E o gba ebun iwe akagbadun wa meji lofe, okan lede Yoruba ati ekeji ni ede Oyinbo

09/09/2016

Ijile oro

7.
Baawi, a o Ku, bi ako si wi Orun la n lo.

Ki kaluku o maa ranti ati sun, ki amaa ranti ojo tina o dile leyin asunsuje.

Alore n ke.

13/07/2016

IJILE ORO ....... 6

Botiwu ka pe laye to, a o pe l'Orun ju bee lo.
E je ki a maa hu'wa bi eni ti ko nii d'ola, nitori wipe:

' Ki a mase tanyin je, a ko lee gan Olorun, ohunkohun ti eniya ba furugbin, oun ni yoo ka.

02/07/2016

IJILE ORO ....... 5

'' ENI EGUNGUN N LE, KO MAA ROJU, B'OSE N RE ARA AYE, BEE LO N RE ERO ORUN ''
IF'ORITI LONI OHUN GBOGBO.

EJE KA GBAGBO WIPE, OLORUN KO GBAGBE EMI ATI IWO.

Address

Oluwatedo Street
Tapa

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ijile oro lat'ori Ite _ Alore n ke posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share