Itusile Iseda - Deliverance of Inner-Man

Itusile Iseda - Deliverance of Inner-Man MO SI OJU OPO YI SI LE GEGE BI IDARE EMI OLORUN. OGUN TI KO BA LE BO RI ISEDA RE KO LE BO RI RE.

YOUR INNER MAN WILL BE DELIVERED TONIGHT IN JESUS NAME.
20/11/2023

YOUR INNER MAN WILL BE DELIVERED TONIGHT IN JESUS NAME.

Mo fí ọpẹ fún OLÙWÀ to fún ní ore-ọfẹ láti mọ Iwọ ti onyọ pẹlu mi. Mo kí ọ fún Orire,mo gbè ọwọ mi sókè sí Olódùmarè, ẹn...
22/07/2023

Mo fí ọpẹ fún OLÙWÀ to fún ní ore-ọfẹ láti mọ Iwọ ti onyọ pẹlu mi. Mo kí ọ fún Orire,mo gbè ọwọ mi sókè sí Olódùmarè, ẹni tí o ní gbogbo agbára.

Fí ìtara ṣe Amin....

* Idaamu rẹ dopin ni Orúkọ JÉSÙ..

*Ohunkóhun tí o bá nà ọwọ́ rẹ̀ fún, yíò yọrí sí rere..

*Olóore tí Olórun Yàn fún ọ, yíò wá ọ ríi ni Orúko Jésù

*Ẹnikẹni tó bá fé dì ọ lọwọ ní Olórun a mu kúrò ní ORÚKỌ JÉSÙ... Àmín

Òní ní ojó ìbí mi...🎂

Ọ le pé mí fún isure,

Ti ọ ba wun ọ lati fí ẹbùn ọjọ ìbí ranṣẹ sí mí...

*176189290* ->Polaris Bank,
Victoria.O.Olawoye

Màmá wégún w'epe

( For confirmation, you can please send the screenshot on this number
07025843740)...
THANKS AND GOD BLESS 🙏

Join me sing Hallelujah this month, because you will succeed in all your ways and my God will prosper you in Jesus name,...
02/07/2023

Join me sing Hallelujah this month, because you will succeed in all your ways and my God will prosper you in Jesus name, Amen!

Prophetess Victoria Olawoye
a.k.a Mama Wegun W'epe

SE O MO PE IWO NI ORIRE KAN??? Yara se amin Adura Yii pelu igbagbo.* Wa rii iranlowo gba l'ose yii.* Wa gba leta ORIRE* ...
16/01/2023

SE O MO PE IWO NI ORIRE KAN???

Yara se amin Adura Yii pelu igbagbo.

* Wa rii iranlowo gba l'ose yii.
* Wa gba leta ORIRE
* Enikeni to ba fe duro bii alatako si iserere re, ile yio gbemii ni Oruko Jesu.
Amin.

Jade lo ni ose yii kio si lo serere.

Pada wa pelu eri to d'aju ni Oruko Jesu
Amin!!!

Prophetess V.O. Olawoye
a.k.a Iya wegun wepe.

Mo ki gbogbo eniyan ku orii re, Eku igbese si inu osu titun.Mo ba iseda re dupe nitori Olorun tu e sile,Iseda re si ti w...
01/01/2023

Mo ki gbogbo eniyan ku orii re,

Eku igbese si inu osu titun.

Mo ba iseda re dupe nitori Olorun tu e sile,

Iseda re si ti wo inu Odun titun t'ogo t'ogo.

Ni Oruko Jesu, wa rii OGO naa lo....

E ku odun o...🎇🎇🎇

Prophetess Victoria O. Olawoye.

The Month is going to and End Brethren!Believe the Word of God from my mouth. "Your problem is going to an end in Jesus ...
24/10/2022

The Month is going to and End Brethren!
Believe the Word of God from my mouth. "Your problem is going to an end in Jesus name".

Prophetess Victoria O.Olawoye

Address

Sango Otta

Telephone

+2348030813202

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Itusile Iseda - Deliverance of Inner-Man posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Place Of Worship

Send a message to Itusile Iseda - Deliverance of Inner-Man:

Share