19/05/2020
*PRAYER POINTS FOR 19/05/20 PRAY WITH EXODUS 15:9-10, PSALM 35*
1. Locate a worship song to exalt the Lord.
2. I refuse to be a blind Christian in the name of Jesus.
3. Anywhere my name or picture is mentioned for evil, fire and thunder of the Lord consume them in the name
of Jesus.
4. Every secret that I need to know about activities of the
enemies in my life, be revealed now in the name of Jesus.
5. Call the name of Jesus 21 times and pray that every
strange thing that the strange voice of the enemy has planted into my life catch fire and explode in the name of Jesus.
6. Every power sent to throw my life into spiritual
darkness be wasted in the name of Jesus.
7. The voice of the enemy that has turned to flesh
following me about get behind me by fire in the name of Jesus.
8. Everything that has been killed in my life by the voice of darkness resurrect again in the name of Jesus.
9. The voice of the Lord swallow the voice of darkness in my life in the name of Jesus.
*KOKO ADURA FUN 19/05/20 GBADURA PELU EKSODU 15:9-10 ORIN DAFIDI 35.*
1. Wa orin ope kan fi gbe Oluwa ga.
2. Mo ko lati je Kristeni afoju l'oruko Jesu.
3. Ibikibi ti won ba ti daruko mi tabi fi aworan mi han fun ibi, ina ati ara tu won ka l'oruko Jesu.
4. Gbogbo asiri ti mo ni lati mo nibiti ota ba ise de laiye
mi, Emi-Mimo tu fun mi l'oruko Jesu.
5. Pe ina Emi-Mimo ni igba mokanlelogun, gbadura
wipe gbogbo ohun ti a fi ohun okunkun gbin si inu iye mi, gbina daanu l'oruko Jesu.
6. Agbara ti won yan lati so mi si nu okunkun t'emi, sofo daanu l'oruko Jesu.
7. Ohun ota to ti di ara to ntele mi kiri, pada pelu ina
l'oruko Jesu.
8. Gbogbo ohun ti a fi ohun okunkun pa mo mi lar, ji
pada l'oruko Jesu.
9. Ohun Oluwa gbe ohun okunkun mi ninu aiye mi
l'oruko Jesu.