14/07/2026
Mo ki gbogbo ile ooo, Alafia olorun alaye ki o ma ba gbogbo eyin ti E hun ka post mi yi,..modupe lowo olorun oba, fun awon asiri ise ti mo hun post sinu group yi, nitori awon eniyan kokan hun pemi lati dupe Lori awon ise na ti won se,ti won siri iyipada gidi, Baba kan pemi lati kaduna ni ose ti o lo yi, lati dupe, E se o, ohun ti E hun dupe le lori ko ni dibaje ni oruko Jesu, Asiri ise eleyi ti mo mun wa Loni ni,- 💯 ( 💯 ),,. Gbogbo eni ti ona ti di mo patapata, ti ati je ati mun di ogun fun, Iwo ti awon customer ko wa si odo re mo,Iwo ti won tin fi oju egan wo o lawujo, wipe o le ri okotabi aya fe,abi o le ni igbega lenu ise re,ki o lo gbiyanju ise yi, iwo ti ise ki dahun lara re, lo gbiyanju ise yi,ki o ri titobi agbara olorun oba,Ise yi mi fe, ki a ko sile lasan o, E je ki a lo gbiyanju re, ki a wa fun ile labo, Ise na niyi-Ao get Ewe Owon, e ma je ki won fun wa ni ewe miran o,moti fun enikan ni asiri ise yi ri,ti won lo gbe ewe owo le lowo, ti e ba ti de ibi ti E ti fe ra ewe yi,E o so Wipe Ewe Owon pabida sobi dire ni E fe ra, yio ti ye awon ti E fe ra lowo won, leyin eyi ki E wa get ewe sawerepepe oojo tabi tutu, ewe oparun die,ati ewe alupaida,.pelu ose eyikeyi ti a ba fe lo,..Sise re,- Ao gun gbogbo awon ewe yi papo ti yio kuna dada, ao wa pomo ose ti a fe lo, ao wa ko sinu ike funfun olomori ,ao wa gba adura si bi a se fe,, Lilo re,- Ao ma fi we ni Monday ati Thursday, abi Friday, Emeji lose ni wiwe ose Yi,.Ise ti o daju ni iseyi...majemu ise yi ni ki odupe ki ise yi ba le je fun o, .Ise yi wa nile bayi, fun iwo ti o ba le raye lati se, tabi fun eyikeyi eto adura, ki E pemi tabi ki E message mi nibi tabi Whatsapp @08063529338,. Imole 🕯️