13/10/2023
.. life is Spiritual...
EWO ERANKO LASAN TI OLORUN FI IROBI ATI IBIMO RO LORUN, NIBI TI ENIYAN TIN SE WALA ATI IRORA PUPO BIMO. IROYN GBE WIPE, OKUNRIN KAN NA OWO BI 500,00 LE IYAWO RE LORI NI ILE IWOSAN NITORI KI IYAWO RE LE BIMO TI OSI PAPA PADANU IYAWO RE NITORI AWON DOKIYA NIPE KI OLO WA OWO WA SI...
Amoran fun gbogbo eniyan. E SUN MO OLORUN, KI ESI FI AYE YIN FU JESU KRISTI OLUGBALA KI OLE FI OHUN GBOGBO RO WA LORUN. KI WALA ATI ISORO LE DAPIN PATAPATA...
OGO NI FUN OLORUN LOKE ORUN.