29/06/2022
Ohun yi(Voice) jade si o wipe o ma ri Omo to, Omo ri Omo wo.Awon Omo re ma ye.O ma je ounje Omo.Ota ko ni so awon omo re di Ota re.Ounje Omo ki yio koro lenu re,Aseyori ko ni je Eewo fun awon omo re.
A o si iboju tabi isiju okunkun kuro loju awon omo re,ki won le sanu fun ooo.Awon Omo re ma je ogo fun o,beni won yio je Ogo fun orile Ede.
Say this:
EMI YIO JEUN OMO!!!!