Adura Isegun kuro Lowo Ota

Adura Isegun kuro Lowo Ota The Page is All About Cristianity Prayer...To Deliver People Out Of Bo***ge of Dackness. along Ikirun road, back of machine tools osogbo, osun state.

24/07/2026

Good night everyone

TI ELISA BA KOJA LOSI ORISUN OMI,TO SI SE AWOTAN IKORO RE...............Bi Oluwa ti nbe ti Emi re si nbe laaye sibe:    ...
24/07/2026

TI ELISA BA KOJA LOSI ORISUN OMI,TO SI SE AWOTAN IKORO RE...............Bi Oluwa ti nbe ti Emi re si nbe laaye sibe: Gbogbo ikorita ti eti nja ogun ipile........Anu Oluwa tu yin sile.....Orisun yin ko bere sini sun didun.......Ipile yin ko mu itura wa fun yin lati oni loruko Jeeeeeesu kristi amin πŸ™πŸ½πŸ™πŸ½πŸ™πŸ½

Ni oruko Jesu gbogbo alagbara to di-gaga mo ogo ayanmo re toni oun koni jeki eri ona lo,afi ti oun ba ku loku..............
24/07/2026

Ni oruko Jesu gbogbo alagbara to di-gaga mo ogo ayanmo re toni oun koni jeki eri ona lo,afi ti oun ba ku loku............Idajo agbara ti A se fun HAMANI nitori oro MODIKAI iru eda be ko ku iku ojiji lori oro re loruko Jesu kristi amin amin

22/07/2026

OGUN T'OUN P'ANA OGO,LATI ONI LO KO TUN LAGBARA LORI AYE YIN MO Amin.

22/07/2026

Big shout-out to my newest top fans! Miopebore Isese Lagba, Evang Oni Joshua Imisi, Bukky Ayanfe, Omolara Joshuafm, Elijah Oluwajoba Asubiojo, Dayo Oladayo, Howolarbhi Horlarmeedey Adejare, Bose Ajayi

Ni oruko Jesu kristi,bi e'ti n jade lo loni.....Eni se ko-n'ge aburu Iseda yin koni gbabode ibi Eni rin arin-fe-se-si Og...
22/07/2026

Ni oruko Jesu kristi,bi e'ti n jade lo loni.....
Eni se ko-n'ge aburu
Iseda yin koni gbabode ibi
Eni rin arin-fe-se-si
Ogun ateyinja koni ja yin
Eni bo si owo a-so-ni-mu tomo tomo........
✝️NI ORUKO JEEEEEESU KRISTI .AMIN ni ko se.

Ni oruko Jesu,gbogbo owo adani duro s'oju kan lori ogo ayanmo re........Ni oruko Baba,Omo,Emi mimo.....ko l'ana danu lon...
21/07/2026

Ni oruko Jesu,gbogbo owo adani duro s'oju kan lori ogo ayanmo re........Ni oruko Baba,Omo,Emi mimo.....ko l'ana danu loni.
Amin amin amin πŸ™πŸ½...

20/07/2026

NI ORUKO JESU,ENI TI OJU OORUN DE OJU IKU NI ASE EDUMARE πŸ™πŸ½πŸ™πŸ½πŸ™πŸ½

20/07/2026

Address

Osogbo

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Adura Isegun kuro Lowo Ota posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share