Prophet Micheal Toluwalase Ministry

Prophet Micheal Toluwalase Ministry WITH GOD ALL THINGS ARE POSSIBLE
(1)

14/08/2026

Gbogbo ipejọpọ to se lodi si ogo re ọwọ da won loro
Every gathering against your glory hand of God destroy them
Your sorrow will turn to testimony

05/08/2026

#

ÌFIHÀN 5:12-14[12]Nwọn nwi li ohùn rara pe, Yiyẹ li Ọdọ-Agutan na ti a ti pa, lati gbà agbara, ati ọrọ̀, ati ọgbọ́n, ati...
04/08/2026

ÌFIHÀN 5:12-14
[12]Nwọn nwi li ohùn rara pe, Yiyẹ li Ọdọ-Agutan na ti a ti pa, lati gbà agbara, ati ọrọ̀, ati ọgbọ́n, ati ipá, ati ọlá, ati ogo, ati ibukún.
Saying with a loud voice, Worthy is the Lamb that was slain to receive power, and riches, and wisdom, and strength, and honour, and glory, and blessing.
[13]Gbogbo ẹda ti o si mbẹ li ọrun, ati lori ilẹ aiye, ati nisalẹ ilẹ, ati irú awọn ti mbẹ ninu okun, ati gbogbo awọn ti mbẹ ninu wọn, ni mo gbọ́ ti nwipe, Ki a fi ibukún ati ọlá, ati ogo, ati agbara, fun ẹniti o joko lori itẹ́ ati fun Ọdọ-Agutan na lai ati lailai.
And every creature which is in heaven, and on the earth, and under the earth, and such as are in the sea, and all that are in them, heard I saying, Blessing, and honour, and glory, and power, be unto him that sitteth upon the throne, and unto the Lamb for ever and ever.
[14]Awọn ẹda alãye mẹrin na wipe; Amin. Awọn àgba mẹrinlelogun na wolẹ, nwọn si foribalẹ fun ẹniti mbẹ lãye lai ati lailai.
And the four beasts said, Amen. And the four and twenty elders fell down and worshipped him that liveth for ever and ever.
Only Jesus can do it, believe in the light that darkness can not comprehend.
I pray you will have joy in Jesus mighty name

02/08/2026

God of perfection will do your own this month in Jesus mighty name

01/08/2026

This month You will not cry over your life
It will be your month of joy

01/08/2026

Amin loruko jesu

31/07/2026

God of perfection 2026

31/07/2026

OLORUN ALASEPE
GOD OF PERFECTION
ORU ASEPE (NIGHT OF PERFECTION)
AMIN NI KO SE
KOTO JU OLUWA YIO DA Ọ LOUN AYỌ
BEFORE IT'S LATE GOD WILL ANSWER
YOU

God of perfection, day 1
30/07/2026

God of perfection, day 1

30/07/2026

Can you praise God for a minute

Address

Osogbo

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Prophet Micheal Toluwalase Ministry posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share