Isaac Obidiya

Isaac Obidiya This is a religious platform where I share the words of God; about salvation, doctrines, motivational, etc.

16/05/2026

Pastor G. O. Odelade ministering during Segan mi dogo program at Ondo Women's Convention.

Celebrating my 4th year on Facebook. Thank you for your continuing support. I could never have made it without you. 🙏🤗🎉
20/02/2025

Celebrating my 4th year on Facebook. Thank you for your continuing support. I could never have made it without you. 🙏🤗🎉

IDANILEKO FUN TI OJO OLUWA 26/02/2023.EKO KEJO (8): JESU NGBADURA BI AKOKO SE HA FUN TÓ.Bibeli Kika: Maaku 1:35-39. a. I...
21/02/2023

IDANILEKO FUN TI OJO OLUWA 26/02/2023.
EKO KEJO (8): JESU NGBADURA BI AKOKO SE HA FUN TÓ.
Bibeli Kika: Maaku 1:35-39.
a. Ilepa Eko: Lati fihan pe Jesu ri bi adura se se pataki to ti o fi wa aaye lati se e.
b. Ese Akosori: O si pa owe kan fun won nitori eyi yi pe o ye ki a ma gbadura nigba gbogbo, ki a ma si se aare. Lk. 18:1.
d. Awon Orin Ti O Ba Eko Mu: Orin Irapada 532, Akokun 270.
e. Alaye Lori Eko:
Ila kinni si ikerin (i.- iv.) Nse alaye lori bi okiki Jesu se ntan kaakiri ti opolopo eniyan ndaniyan lati ri Jesu; kiise nitori oro iwaasu re, sugbon nitori awon ise iyanu ti Jesu nse laarin won; eleyi tile jo awon omo eyin Jesu loju de ibi wipe won lo kede fun ni ese 37 iwe Maaku ori kinni yen wipe awon eniyan mbeere re; sugbon Jesu ko je ki eyi gbe oju on kuro lara idi pataki ti o fi wa saye; eyi ni lati waasu ijoba Olorun.
Eko wo lo ye ki emi ati iwo ko lara Jesu nibiyi oun ni wipe a ko gbodo fi aaye gba ohunkohun ki o gba eto Olorun ati ife re kuro ni okan wa.
Ni ila karun (v) ni a ti rii wipe adura ati ajosopo ti o dan moran wa laarin Jesu ati Olorun ninu eyi ti a ri Jesu pe opolopo igba ni o ma ngbadura. Eleyi si je iranlowo fun lopolopo lati se aseyori ninu ise-iranse re. Nitori naa o ye fun awa naa lati je aladura fun aseyori wa.
Ila kefa ati ikeje (vi - vii) lo je ki o ye wa wipe eniyan lee je eniti ise-iranse ro lorun lati looto sugbon ti ko nii ko ibi ara adura gbigba ati oro Olorun kika iru awon bee ko lee se aseyori lai je wipe won fi Jesu se awokose. Ati wipe bi ise iranse adura ati iwaasu se je Jesu logun lo ye ki o je awa naa logun. Oore Ofe lati je ki eyi ri bee fun wa ki Oluwa fii fun wa.
Fun ibeere ati alaye siwaju sii, e pe number yii:08053086399 tabi 08027138355.

Tomorrow Is YourDay My Queen ADEKEMI Obidiya When You'llClock Yet AnotherYear!
12/10/2022

Tomorrow Is Your
Day My Queen ADEKEMI Obidiya When You'll
Clock Yet Another
Year!

27/07/2021

I am Delighted Today
For Celebrating The
New Age Of My Son.

21/05/2021

She Added A Year To Her Age. HBD.

21/05/2021

She Added A Year To Her Age.

06/05/2021

Happy Birthday To You Emmanuel, My First Issue As A Family Man.

To Restructure Your Destiny? No Way!
11/03/2021

To Restructure Your Destiny? No Way!

Please Finish Your Training in time
06/03/2021

Please Finish Your Training in time

Address

Ondo
36

Telephone

+2348053086399

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Isaac Obidiya posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Place Of Worship

Send a message to Isaac Obidiya:

Share