Prayer with testimony Evangelical ministry. by prophet: adeyemi Ibukun

  • Home
  • Nigeria
  • Ojo
  • Prayer with testimony Evangelical ministry. by prophet: adeyemi Ibukun

Prayer with testimony Evangelical ministry. by prophet: adeyemi Ibukun Akingbile moniya ibadan,Oyo state

19/08/2023

Ánu tó gbe ìdájọ mí ko wá ọ kan lórúko Jesu

Ni gbogbo ibí ti oti sọ ireti nu, tabi ti awọn eniyan ti sọ ìrètí iṣere nú lori rẹ, ohun títún ati ohun ayọ ti yíó sọ ìr...
22/07/2023

Ni gbogbo ibí ti oti sọ ireti nu, tabi ti awọn eniyan ti sọ ìrètí iṣere nú lori rẹ, ohun títún ati ohun ayọ ti yíó sọ ìrètí rẹ di ògo fún ọ, ọlọrun gbé le ọ lọwọ lórúko Jesu kristi ti Nazareti

20/07/2023

Níbi wón ti mu ọ lẹru ri, nibi ti won ti kọ sílẹ nigba kan ri, Mo palaṣẹ loruko Jesu o ma di aláṣẹ níbè. Ẹgàn rẹ di ògo

ORIN DAFIDI 34:5[5]Nwọn wò o, imọlẹ si mọ́ wọn: oju kò si tì wọn.Mo gbàdúrà fún ọ loni, imọlẹ ògo ko mọlẹ yi Aye rẹ ká l...
12/05/2023

ORIN DAFIDI 34:5
[5]Nwọn wò o, imọlẹ si mọ́ wọn: oju kò si tì wọn.
Mo gbàdúrà fún ọ loni,
imọlẹ ògo ko mọlẹ yi Aye rẹ ká lórúko Jesu
Imọlẹ Ánu ko yí ayé rẹ ká lórúko Jesu
Imọlẹ ojú rere ọlọrun kó yí ayé rẹ ká lórúko Jesu
Imọlẹ fún ìrànlọ́wọ́ láti ibì gíga ko yí ayé rẹ ká lórúko Jesu
Imọlẹ ọlọrun kó mú ìtìjú kuro loju ọ̀na rẹ lórúko Jesu
Gbogbo okunkun loju ọ̀na rẹ ìmọle ọlọrun gbé mi loruko Jesu
Wa ni ọjọ ẹri rere lórúko Jesu kristi Àmín

Olorun òní Majẹmu ayọ, ko fi ayọ púpọ sínú Irinajo osu tuntun yii fún ọ lórúko Jesu.Òhun tuntun ti ọkàn rẹ fẹ lati ọjọ p...
01/05/2023

Olorun òní Majẹmu ayọ, ko fi ayọ púpọ sínú Irinajo osu tuntun yii fún ọ lórúko Jesu.
Òhun tuntun ti ọkàn rẹ fẹ lati ọjọ pipẹ lórúko Jesu kò tẹ ọ lọwọ ni oṣù yii
Irinajo osu karun yìí kò bi ẹri rere fún iwọ àti ìdílé rẹ lórúko Jesu kristi ti Nazareti Àmín

25/04/2023

Everyone that is journey with U, that is sending goodness&joy away from U, powerful hand of God will do separation in Jesus name

AISAYA 60:1[1]DIDE, tàn imọlẹ: nitori imọlẹ rẹ dé, ogo Oluwa si yọ lara rẹ.Mo gbàdúrà fún ọ pé.✳️Òkùnkùn Aye oni borí im...
17/04/2023

AISAYA 60:1
[1]DIDE, tàn imọlẹ: nitori imọlẹ rẹ dé, ogo Oluwa si yọ lara rẹ.
Mo gbàdúrà fún ọ pé.
✳️Òkùnkùn Aye oni borí imọlẹ ògo rẹ lórúkọ Jésù
✳️ Imọlẹ ogo rẹ kò di mi mọn ni gbogbo ayé
✳️ Imole ayọ rẹ koni wọ òkun lórúko Jesu
✳️ Gbogbo idajọ okunkun lori iwọ àti ìdílé rẹ ìmọle ọlọrun yi dànù kúrò lórí yín lórúko Jesu
✳️ Imọlẹ, fún ìrànlọ́wọ́, fún ánu, fún ojú réré ko yí ọ ká lórúko Jesu kristi (Àmín)

20/06/2022

Every of devil against your life that say u work and it successful but u will not enjoy it, shall be scatter in Jesus name

I declare with authority from the anointing of grace, God will transform you from nobody into great person without taken...
07/04/2022

I declare with authority from the anointing of grace, God will transform you from nobody into great person without taken permission from anybody in Jesus name🔥🔥🔥🔥🔥

PRAYER FOR TUESDAY➡️God almighty will comfort all afflicted area of your life in Jesus name➡️ God of Abraham will comfor...
05/04/2022

PRAYER FOR TUESDAY
➡️God almighty will comfort all afflicted area of your life in Jesus name
➡️ God of Abraham will comfort all your wasted place in Jesus name
➡️God will transform wilderness of your life into Eden and your desert into garden of the lord in Jesus name
➡️Joy and gladness shall be found in your House with the Thanksgiving and voice of melody all the days of your life in Jesus name (Amen) kindly share/send your prayers request on WhatsApp:07063007366

03/04/2022

RECEIVE IT WITH YOUR AMEN 🙏 AND SHARE

Address

Ojo

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Prayer with testimony Evangelical ministry. by prophet: adeyemi Ibukun posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Place Of Worship

Send a message to Prayer with testimony Evangelical ministry. by prophet: adeyemi Ibukun:

Share