Ona iwa mimo cherubim and seraphim nigeria & overseas

Ona iwa mimo cherubim and seraphim nigeria & overseas Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Ona iwa mimo cherubim and seraphim nigeria & overseas, Religious organisation, Ogbomosho.

Few more weeks to our upcoming camping program and anniversary @ The Brigade Band of Ona Iwa  Mimo  Cherubim & Seraphim ...
26/07/2018

Few more weeks to our upcoming camping program and anniversary @ The Brigade Band of Ona Iwa Mimo Cherubim & Seraphim Ogbomoso, Imole Kristi district.

19/10/2017

Here comes another year on heart, annual programme @ Igboho, Oyo state. A week to go, everybody was invited.

05/09/2017

Dídùn dídùn ni ìrántí olódodo àti àwon akoni to ti fi idà lélè nínú kristi jesu, èyíni làti kéde ìrántí bàbá wa Snr. pro. Moses Adegoke Oladejo, ti ìjo Ona Iwa Mimo C&S Church Oke-ado, oke iye, ogbomoso. Bayi ni ètò ìrántí yó se lo, 6th - 10th September, 2017, Ìsojí àti ìsó-òru pèlú ìdúpé. Sun ree ooo bàba wa Adegoke.

Iku pa abiri, abiri ku, Iku pa abiri abiri rorun alakeji, iku pa akoko, omi agbe n sofo, eyi ni lati kede iku akogun wa ...
14/12/2016

Iku pa abiri, abiri ku, Iku pa abiri abiri rorun alakeji, iku pa akoko, omi agbe n sofo, eyi ni lati kede iku akogun wa Queen Captain Mary Ogunyooye, eniti o sun ninu oluwa, bayi ni ojo isinku yo se lo ni ojo kerindinlogun ati ketadinlogun osu kejila odun yi (16/17) ninu ijo olorun C&S Church Ona Iwa Mimo, Ojota, Lagos. Olukede awa ijo mimo C&S Ona Iwa Mimo, Oke-ado, Imole kristi district, ogbomoso.

03/03/2016

Blessed be thy name Oh Lord, for mercy and goodness over your.
We also glorify your for the life of Mai brother, he start in the of you, still continue for your sake. Jehovah Rammah, Jevoah Adonai.

21/12/2015

Olorun Ona Iwa Mimo O seun fun anu re lori gbogbo awa Omo re lapapo, adupe, a yin ooo.....

04/12/2015

The year is going to an end In JESUS NAME,, our LIFE will nt go to an end... Happy New Month in advance....

30/10/2015

Olorun Adeola adupe ayin oooo fun lilo bibo wa lo si ori~oke adupe fun irinajo wa tori enikan kan o subu nitori na awa yin oooooo... On behalf me nd my Warbay guy...

13/10/2015

A ku orire ooo eyi ni lati fi ran gbogbo eyin omo Ona Iwa Mimo leti wipe ajodun ori oke wa ku si dede,oju wa yo rodun amin oooo, ti yin ninu kristi
Lati owo Olayinka Ayomide a.k.a. Omo Arikewusola.

22/09/2015

Hurray ! Hurray!! Hurray!!! OIM annual pilgramme is knocking nw at. Igboho finz....

22/09/2015
22/09/2015

Olorun Ona Iwa Mimo O seun over my Life
Admission finz on my gaily mind at Nigeria Defence Academy....

Address

Ogbomosho

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ona iwa mimo cherubim and seraphim nigeria & overseas posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share