FIRST BAPTIST CHURCH OKELERIN OGBOMOSO

FIRST BAPTIST CHURCH OKELERIN OGBOMOSO This is the official page of First Baptist Church Okelerin Ogbomosho Oyo State

26/08/2026

PRAYER BURDEN FOR THE DAY/ATENUMO ADURA FUN OJO TO 'NI
(THURSDAY AUGUST 27, 2026)

Using Genesis 39:2-3, pray that all NBTS Old and New Students worshipping with FBC, Oke’lerin will become outstanding in their training. Pray for personalized encounters for all participants at the ongoing Fasting and Prayer Congress./ Ni lilo Jenesisi 39:2-3, gbadura ki awon Akeko Titele ati Titun n’ile Eko Oniwasu ti n josin ninu Ijo FBC ma a tayo ninu eto eko won. Gbadura fun ibapade olodanni fun awon olukopa ninu Ipade Aawe ati Adura to n lo lowolowo.

26/08/2026

BIBA OLORUN PADE LOJOOJUMO 2026

AUGUST 27 THURSDAY, 2026

QMQ-QDQ RERE ATI OLOOTO

Bibeli Kika: Matiu 25:14-23

Oluwa re si wi fun un pe, o seun, iwo̟ o̟mo̟-odo rere ati olooto, iwo se olooto ninu ohun dię, emi yoo mu o se olori ohun pupo; iwo bo sinu ayo oluwa rę! Matiu 25:23.

YBH 346: Ao Sise! Ao Sise! Om'Olorun Ni Wa

KBJL: Esikieli 13-15

A gbo itan omo-odo obinrin kan eni ti o da idile ti o gba a s**o nipa fifun awon ajinigbe ni iroyin ti o ṣe okunfa bi wọn ti ji iyawo oga re gbe lo. O ti darapo mọ idile naa ki o to pe omo odun mewaa, won si ti fi ife gba a gege bi omo won. Won fi oruko re sile ni ile eko alakobere aladani pelu ọmọ kan soso ti wọn bi, wọn si tun ran an ni ile iwe girama.. ọjọ kan, wọn ji iyawo oga re gbe; leyin igba ti owo te awọn ajinigbe naa ni otito ti o yani lenu yii je jade: omo-odo yii ni o fun awon ajinigbe ni iroyin ti o ṣe koko ti won nilo lati huwa odaran naa.

Ninu abala eko ti oni, oluwa naa fun awon omo-odo rẹ meta ni talenti, pelu ase pe ki won fi sowo ki won si jere pelu awọn talenti naa. Nigba ti awọn meji akoko fi ara wọn han gege bii olotito, ti won si fi idi igbekele ti oluwa won ni ninu wọn mulę, omo-odo keta fi ara han bi eni ti ko ye ti ko si bikita. Abala eko naa se afihan re pe imoyi ati ere wa fun omo-odo rere ati olododo; iru omo-odo bee ni a o fun ni ojuse ti o po sii, ibukun pupo yoo si je ipin re.

Kin ni o ti se pelu talenti ti Olorun ti fi fun o? Nigba ti O ba pada de, nje Yoo pe o ni omo-odo rere ati olooto? Gege bi oluwa ti a ka ninu abala eko ti oni, Jesu Kristi n bo laipe, eyi ti o tumo si pe ojo ijihin sunmo tosi. O si ni akoko lati lo ohun ti O fi fun o daadaa lati mu ere sii wa si Ijoba Re. Bi o ba je alaiṣododo, ronupiwada ni kiakia, ki o si di olotiito, mura si ise, ki o si di eni to n seso ninu ogba ajara Re.

• Oro Ogbon: Imoyi ati ere wa fun gbogbo omo-odo rere.

• Oro fun Ironu: Kin ni o o wi fun Jesu Kristi nigba ti O ba beere bi o se lo akoko, talenti, ati awon ohun ini ti O fi si ikawo re?

• Ise Şise: Tokasi ibi kan (paapaa julo ninu ijo re) nibi ti o ti lo talenti re ni ose yii.

• Adura: Oluwa owon, je ki n gba imoyi, ma je kin gba idalebi ni akoko ti O ba arahan ni orukç Jesu. Amin.

Gbadura fun awon Eni-Owo wonyi, idile ati awọn omo Ijo Olorun: Nosa Omo-Ogbebor, Ibadan; Awosola Richard T., Işeyin; Akande Lawrence O., Eko; Oyebisi John T., Eko; Adeyemi J. Famoroti, Oyo; Adeyemi E. O. Ayo, Abeokuta; Mpakaboari George, Eleme; Oyetunji J. Olusanjo, Ogbomoso; Iyanda John A., Ogbomoso; John O. Kehinde, Ibadan; Adeyemo J. Adebayo, Ibadan; J.F. Adelaiye, Isanlu; Christopher O. Osagiede, Benin.

Oluwa, fun wa ni okun lati gbe gbogbo ihamora Olorun wo ki a si duro sinşin lati koju ija si arekereke eşu. Fi ami ororo yan awọn akekoo pelu agbara Emi, okun, imo, oye, imoran, ogbon ati eru Oluwa bi ipade apapo awon odo kaakiri agbaye yoo se bere ni Yunifasi Bowen, Iwo ni oni.

EBĘ ADURA FUN AUGUST: Oluwa, ran awọn ọdọ ati Akekoo lowo lati se awari eredi aye wọn ninu Ręki won si mu un se, ni oruko Jesu (Johanu15:4).

26/08/2026

DAILY ENCOUNTER WITH GOD (2026)

AUGUST 27 THURSDAY, 2026

GOOD AND TRUSTWORTHY SERVANTS

Text: Matthew 25:14-23

'His master replied, "Well done, good and faithful servant! You have been faithful with a few things; I will put you in charge of many things. Come and share your master's happiness!" Matthew 25:23, NIV

BH 435: To the Work

RBT: Ezekiel 13-15

A story was told of a housemaid who betrayed the family that took her in by providing information to kidnappers, leading to the abduction of her master's wife. She had joined the family before the age of ten, and they had lovingly accepted her as one of their own. They enrolled her in a private primary school alongside their only child and later sponsored her through secondary school. One day, her master's wife was kidnapped; it was only after the kidnappers were apprehended that the shocking truth emerged: the housemaid had been the one who supplied them with the vital information needed to carry out the crime.

In today's passage, the master entrusted his three servants with talents, instructing them to trade and make a profit with the talents. While the first two servants proved themselves faithful and justified the trust placed in them, the third servant showed himself to be unworthy and irresponsible. The passage reveals that there is commendation and reward for any good and faithful servant; such a servant shall be trusted with more responsibilities, and greater blessings will be their portion.

What have you done with the talent God has given you? When He returns, will He call you a good and faithful servant? Like the master in today's passage, Jesus Christ is coming soon, meaning the day of accountability is near. You still have time to maximise what He has given you to bring more profit to His Kingdom. If you are unfaithful, repent immediately and become faithful, diligent, and productive in His vineyard.

• Wisdom: There is commendation and reward for every good servant.

• Food for Thought: What will you say to Jesus when He asks how you used the time, talents, and resources He entrusted to you?

• Follow-up Action: Identify a place (especially in your local church) where you will use your talent this week.

• Prayer: Dear Lord, may I receive commendation and not condemnation at You appearance, In Jesus' Name. Amen!

Pray for these ordained ministers and members of their churches: Nosa Omo-Ogbebor, Ibadan; Awosola Richard T., Iseyin; Akande Lawrence O., Lagos; Oyebisi John T., Lagos; Adeyemi J. Famoroti, Oyo; Adeyemi E. O. Ayo, Abeokuta; Mpakaboari George, Eleme; Oyetunji J. Olusanjo, Ogbomoso; Iyanda John A., Ogbomoso; John O. Kehinde, Ibadan; Adeyemo J. Adebayo, Ibadan; J.F. Adelaiye, Isanlu; Christopher O. Osagiede, Benin.

Lord, give us the strength to put on the full armour of God and stand firmly against the wiles of the Devil. Anoint students with the Spirit of power, might, knowledge, understanding, counsel, wisdom and of the fear of the Lord as International Student Conference begins at Bowen University, Iwo today.

AUGUST PRAYER SHOWERS: Lord, help the Youth and Students discover their purpose in You and fulfil it, in Jesus' name (John 15:4).

26/08/2026

SEEK DAILY (NBC)

Thursday, August 27

RBT Passage: Ezekiel 13-15

WORK HARD, GIVE, TRUST IN GOD

Memory Verse: "Those who work their land will have abundant food, but those who chase fantasies will have their fill of poverty. The stingy are eager to get rich and are unaware that poverty awaits them. Those who trust in themselves are fools, but those who walk in wisdom are kept safe." Proverbs 28:19a, 22, 26, NIV

Text: Proverbs 28:18-28

Proverbs 28:18-28 NIV
[18] The one whose walk is blameless is kept safe, but the one whose ways are perverse will fall into the pit.

[19] Those who work their land will have abundant food, but those who chase fantasies will have their fill of poverty.

[20] A faithful person will be richly blessed, but one eager to get rich will not go unpunished.

[21] To show partiality is not good— yet a person will do wrong for a piece of bread.

[22] The stingy are eager to get rich and are unaware that poverty awaits them.

[23] Whoever rebukes a person will in the end gain favor rather than one who has a flattering tongue.

[24] Whoever robs their father or mother and says, “It’s not wrong,” is partner to one who destroys.

[25] The greedy stir up conflict, but those who trust in the Lord will prosper.

[26] Those who trust in themselves are fools, but those who walk in wisdom are kept safe.

[27] Those who give to the poor will lack nothing, but those who close their eyes to them receive many curses.

[28] When the wicked rise to power, people go into hiding; but when the wicked perish, the righteous thrive.

_____________________________
When Grace started a small farm business, she knew it would take her effort and patience. She worked tirelessly, planting, and watering daily. At harvest, she had more than enough for her family and chose to share with her neighbours. Though challenges came, she trusted God to bless her little efforts. Over time, her small farm grew. This reminded her that hard work, generosity, and faith in God always bring lasting rewards.

The scripture reminds us that laziness only leads to poverty, but diligence produces abundance. Hard work is not just about survival, it is also a mark of obedience to God, who Himself is always at work to sustain everything he created. Giving is another of a heart that understands God's provision. Stinginess reflects greed but generosity shows gratitude and contentment. Finally, trusting God is the wisest choice we can make. Human strength and wisdom may fail but those who put their confidence in the lord remain secure.

As believers, we are called to combine diligence in work with generosity and unshakeable trust in God, for these three together open the door to God's blessings.

_____________________________
Insight: Hard work, generosity, and trust in God bring lasting rewards.

Prayer: God, teach me to walk in your ways and avoid all things that contradict your purpose in Jesus' name.

26/08/2026

3RD QUARTER PRAYER CONGRESS

25/08/2026

PRAYER BURDEN FOR THE DAY/ATENUMO ADURA FUN OJO TO 'NI
(WEDNESDAY AUGUST 26, 2026)

Ask God to make FBC, Oke’lerin a biblically sound Church where all members will live in one spirit and one faith (1 Corinthians 12:12-13). Commit the last day of the ongoing Conference in Session to God/. Beere ki Olorun se Ijo FBC ni Ijo ti o munadoko nipa Bibeli nibiti gbogbo omo Ijo o ti ma a gbe ni emi kana ati igbagbo kan (Korinti kinin 12:12-13). Jowo ojo ikehin ti Ajo Ipinle to n lo lowolowo fun Olorun.

25/08/2026

*BIBA OLORUN PADE LOJOOJUMO (NBC YORUBA)*

*WEDNESDAY, AUGUST 26, 2026*

*OBINRIN OLOKOWO TO KAJUẸ*

*YBH 314: Igbagbọ Mi N WọỌ*
IGBAGBO mi nwo O
1. IGBAGBO mi nwo O,
Iwo Od’-agutan,
Olugbala
Jo gbo adua mi,
M’ ese mi gbogbo lo,
K’ emi lat’ oni lo
Si je Tire.

2. Ki ore-ofe Re
F’ ilera f’ okan mi,
Mu mi tara:
B’ Iwo ti ku fun mi,
A! k’ ife mi si O,
K’ o ma gbona t**i,
Ina iye

3. ‘Gba mo rin l’ okunkun,
T’ ibinu yi mi ka,
S’ amona mi,
M’ okunkun lo loni,
N’ omije anu nu,
Lai, ma je ki nsako
Li odo Re.

4. Gbati aiye ba pin,
T’ odo tutu iku,
Nsan lori mi;
Jesu, ninu ife,
Mu k’ ifoiya mi lo,
Gbe mi d’ oke orun
B’ okan t’ a ra.

*Ese Lati Ranti:* O kiyesi i pe ọja oun dara; fitila rẹ ko ku ni oru. Owe 31:18.

*Bibeli Kika: Owe 31:10-22*

[10] Tani yio ri obinrin oniwà rere? nitoriti iye rẹ̀ kọja iyùn.

[11] Aiya ọkọ rẹ̀ gbẹkẹle e laibẹ̀ru, bẹ̃ni on kì yio ṣe alaini ère iṣẹ.

[12] Rere li obinrin na yio ma ṣe fun u, kì iṣe buburu li ọjọ aiye rẹ̀ gbogbo.

[13] Obinrin na yio ma ṣafẹri kubusu ati ọ̀gbọ, o si fi ọwọ rẹ̀ ṣiṣẹ tinutinu.

[14] O dabi ọkọ̀ oniṣowo: o si mu onjẹ rẹ̀ lati ọ̀na jijin rére wá.

[15] On a si dide nigbati ilẹ kò ti imọ́, a si fi onjẹ fun enia ile rẹ̀, ati iṣẹ õjọ fun awọn ọmọbinrin rẹ̀.

[16] O kiyesi oko, o si mu u: ère ọwọ rẹ̀ li o fi gbin ọgbà-ajara.

[17] O fi agbara gbá ẹ̀gbẹ rẹ̀ li ọjá, o si mu apa rẹ̀ mejeji le.

[18] O kiyesi i pe ọjà on dara: fitila rẹ̀ kò kú li oru.

[19] O fi ọwọ rẹ̀ le kẹkẹ́-owú, ọwọ rẹ̀ si di ìranwu mu.

[20] O nà ọwọ rẹ̀ si talaka; nitõtọ, ọwọ rẹ̀ si kàn alaini.

[21] On kò si bẹ̀ru òjo-didì fun awọn ara ile rẹ̀; nitoripe gbogbo awọn ara ile rẹ̀ li a wọ̀ li aṣọ iṣẹpo meji.

[22] On si wun aṣọ titẹ́ fun ara rẹ̀; ẹ̀wu daradara ati elese aluko li aṣọ rẹ̀.

_______

Ọnkọwe kan ti o gbajugbaja sọ nigba kan pe, "Awon obinrin takuntakun ti won ṣe aṣeyọri n fihan pe ẹru ikuna wa lẹjẹ ọta wa ti o di ẹkọ ti o ṣe pataki julọ ninu aye wa (ẹkọ ti o le ran wa lọwọ lati ni aṣeyọri ti o ga lọjọ iwaju!)."

Iwe owe sọrọ pupọ nipa awọn obinrin. Ọna ti o dara ti iwe naa fi pari ni aworan obinrin oniwabajẹ, ọgbọn ti o lagbara, oniruru ọgbọn atinudá ati aamú ti o jinlẹ.

Abala ẹkọ ti oni n gba awa ọdọ ati awọn obinrin aṣeṣẹ gbeyawo nimọran lati jẹ akinkanju, ki wọn si gẹgẹ bi iya Lemueli Ọba ti gbẹ kọ kale.

O ṣe apejuwe rẹ gẹgẹ bi obinrin takuntakun ati onịṣowo ti o ni ọgbọn atinudá lati ṣedaa, lati ṣe eto, ati lati ṣe akoso okowo, o ma n fori la ewu lati mu erongba rẹ ṣe nigba ti o n ṣe akoso ile rẹ.

O maa n misi, o si maa n gbun awọn ara ile rẹ ni kẹsẹ inu, o maa n tan iṣẹ kara-kara fun igba pipẹ ni ọṣan ati ni oru ki o le ni aṣeyọri.

Obinrin ti a ṣe apejuwe ninu abala ẹkọ ti oni jẹ iwuri fun gbogbo onigbagbọ; a le kẹkọọ lara imura iṣẹ, iṣọtitọ, ati ọna ti o n gba pese fun idile rẹ.

Gẹgẹ bii onigbagbọ, ifẹ Ọlọrun ni pe ki o jere, yoo si dara fun ọ ninu gbogbo awọn idawọle rẹ, paapaa julọ fun imugbooro ijoba Rẹ.

Gẹgẹ bii onigbagbọ aṣeyọri, o gbọdọ ko ipa ti o dara lati maa nipa lori aye awọn eniyan ti o wa ni ayika rẹ.

Nje o si n gba Ọlọrun gbọ lati di nla? Kẹpẹ E fun itọni, ati iranlowọ. Olotiitọ ni lati ro ọ lagbara lati mu erongba rẹ ṣe.

*Ọrọ Ọgbọn:* Jẹ ki aṣeyọri rẹ ni gbogbo agbọn aye rẹ ṣe deede pẹlu bi o ṣe n ṣe daadaa ninu ile ati ninu ijọ rẹ.

*Ọrọ fun Ironu:* Bi o ba jẹ wi pe iwọ nikan ni o n jẹ anfaani aṣeyọri rẹ, o ko tii ṣe aṣeyọri niti ijoba naa.

*Iṣẹ Ṣịṣẹ:* Bi o ṣe n gbadura fun idanwo/ikọduro lati bẹrẹ idokowo lati bẹrẹ katakara kanni oṣu yii.

*Adura:* Oluwa, fun mi ni ikọra-ẹni-ni-ijanu ati ọgbọn atinudá lati wa ojutuu si awọn iṣoro, ni orukọ Jesu.

*Adura:* Oluwa, yọ wa ninu gbogbo ibi.

*Gbadura fun awọn Ẹni-Ọwọ wọnyi, idile ati awọn ọmọ Ijo Ọlọrun:* Ayuba Danlami, Dada; Samson Adejumo, Ogbomọṣọ; Kolawole A. Akinlade, Ibadan; Ojoogun O. Timothy, Ibadan; Abayomi A. Ogunkunle, Ibadan; James S. Sati, Mapejuku; Samuel O. Olabisi, Ilorin.

*KBJL: Ẹsikiẹli 9:12*

25/08/2026

*DAILY ENCOUNTER WITH GOD (NBC)*

*WEDNESDAY, AUGUST 26, 2026*

*A CAPABLE AND ENTREPRENEURIAL WOMAN*

*BH 257: My Faith Looks Up to Thee*

1. My faith looks up to Thee,
Thou Lamb of Calvary,
Savior divine!
Now hear me while I pray,
Take all my guilt away,
O let me from this day
Be wholly Thine.

2. May Thy rich grace impart
Strength to my fainting heart,
My zeal inspire;
As Thou hast died for me,
O may my love to thee
Pure, warm and changeless be,
A living fire.

3. While life's dark maze I tread,
And griefs around me spread,
BeThou my guide;
Bid darkness turn to day,
Wipe sorrow's tears away,
Nor let me ever stray
From Thee aside.

4. When ends life's transient dream,
When death's cold, sullen stream
Shall o'er me roll,
Blest Savior, then, in love,
Fear and distrust remove;
O bear me safe above,
A ransomed soul! Amen

*Golden Text:* She sees that her trading is profitable, and her lamp does not go out at night. Proverbs 31:18, NIV

*Text: Proverbs 31:10-22*

[10] A wife of noble character who can find? She is worth far more than rubies.

[11] Her husband has full confidence in her and lacks nothing of value.

[12] She brings him good, not harm, all the days of her life.

[13] She selects wool and flax and works with eager hands.

[14] She is like the merchant ships, bringing her food from afar.

[15] She gets up while it is still night; she provides food for her family and portions for her female servants.

[16] She considers a field and buys it; out of her earnings she plants a vineyard.

[17] She sets about her work vigorously; her arms are strong for her tasks.

[18] She sees that her trading is profitable, and her lamp does not go out at night.

[19] In her hand she holds the distaff and grasps the spindle with her fingers.

[20] She opens her arms to the poor and extends her hands to the needy.

[21] When it snows, she has no fear for her household; for all of them are clothed in scarlet.

[22] She makes coverings for her bed; she is clothed in fine linen and purple.

_______

A renowned writer once said, “These strong accomplished women demonstrate that our fear of failure can be our greatest enemy and that any venture gone awry can actually turn into our most important life lesson (a lesson that helps us find even greater success later!).”

The book of Proverbs speaks extensively about women. How appropriate that the book ends with a picture of a woman of strong character, great wisdom, diverse skills and deep compassion.

Today's passage encourages young and newly married women to be industrious and well behaved in their homes. Solomon gives accounts in the book of Proverbs, a model woman through the words of King Lemuel's mother.

He described her as a woman of great capacity and entrepreneurial skill to create, organise, and manage a business venture, taking risks to achieve her goals while managing her home.

She inspires and motivates her family members, solves their problems, and was very devoted to her goals, working long and hard day and night to achieve them.

The woman described in today's passage serves as an inspiration to all believers; we can learn from her industry, integrity, and resourcefulness.

As a believer, God's desire is that you will be profitable and prosperous in your endeavours, especially for the advancement of His Kingdom

As a successful believer, you should positively impact the lives of people around you.

Are you still trusting God for greatness? Call on Him for guidance, and help. He is faithful to empower you to fulfil your purpose.

*Wisdom:* Let your success in all areas of life be matched by how well you are doing at home and in your local assembly.

*Food for Thought:* If you are the only beneficiary of your success, you are not yet successful in the Kingdom.

*Follow-up Action:* As you pray for God's leading, explore your entrepreneurial ability to start a trade this month.

*Prayer:* O Lord, give me the discipline and skills to solve problems, in Jesus name.

*Prayer:* Lord, deliver us from all evil.

*Pray for these ordained ministers and members of their churches:* AyubaDanlami, Dada; Samson Adejumo, Ogbomoso; Kolawole A. Akinlade, Ibadan; Ojoogun O. Timothy, Ibadan; Abayomi A. Ogunkunle, Ibadan; James S. Sati, Majeuku; Samuel O. Olabisi, Ilorin.

*RBT: Ezekiel 9-12*

25/08/2026

*SEEK DAILY (NBC)*

*Wednesday, August 26, 2026*

*A CAPABLE, ENTREPRENEURIAL WOMAN*

*Golden Text:* “A wife of noble character who can find? She is worth far more than rubies.”
— Proverbs 31:10, NIV

*Text: Proverbs 31:10–22*

[10] A wife of noble character who can find? She is worth far more than rubies.

[11] Her husband has full confidence in her and lacks nothing of value.

[12] She brings him good, not harm, all the days of her life.

[13] She selects wool and flax and works with eager hands.

[14] She is like the merchant ships, bringing her food from afar.

[15] She gets up while it is still night; she provides food for her family and portions for her female servants.

[16] She considers a field and buys it; out of her earnings she plants a vineyard.

[17] She sets about her work vigorously; her arms are strong for her tasks.

[18] She sees that her trading is profitable, and her lamp does not go out at night.

[19] In her hand she holds the distaff and grasps the spindle with her fingers.

[20] She opens her arms to the poor and extends her hands to the needy.

[21] When it snows, she has no fear for her household; for all of them are clothed in scarlet.

[22] She makes coverings for her bed; she is clothed in fine linen and purple.

_______

Belinda Gates is an American businesswoman and philanthropist who co-founded the Bill and Melinda Gates Foundation.

The Bill and Melinda Foundation works to solve health problems of people around the world.

Her capability and commitment as an entrepreneurial woman have not only helped her immediate family but also contributed to assuaging society's health problems.

The passage presented a portrait of a noble and capable entrepreneurial woman, emphasising her preciousness in her skilful and productive lifestyle, and her devotion to the wellbeing of her household.

She is an asset contributing spiritually, emotionally and financially to her family.

Her home becomes a centre of ministry, reaching out to the poor, training her children and domestic workers in true and kind service.

Her husband and children receive joy and are honoured because of her noble character in her society, as she is a good example to other women.

In today's morally corrupt world, we need capable, productive and godly women who can influence their family and society positively and in the way of the Lord.

A true woman of virtue is not a liability but an asset in God's hands.

What kind of person are you becoming for your family and society?

*Insight:* A noble and entrepreneurial woman is useful and valuable in the hands of God.

*Prayer:* God, I pray for grace to be an asset and not a liability to my family and the society in Jesus' name.

*RBT Passage: Ezekiel 9–12*

24/08/2026

PRAYER BURDEN FOR THE DAY/ATENUMO ADURA FUN OJO TO 'NI
(TUESDAY AUGUST 25, 2026)

Help me oh Lord to always look unto You as the author and finisher of my faith to draw many people into Your sheepfold (Hebrews 12:1-2)./ Ran mi l’owo Oluwa lati ma a fi igba gbogbo wo O gegebi olupilese ati alasepe igbagbo mi lati ma a fa opo eniyan si agbo Re (Heberu 12:1-2).

Address

FIRST BAPTIST CHURCH OKELERIN
Ogbomosho
234

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when FIRST BAPTIST CHURCH OKELERIN OGBOMOSO posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share