24/08/2026
Gba adúrà òwúrọ̀ yí kí o sì tẹ àmín
(1) Gbogbo ète àti àbá òkùnkùn lórí ayé mi àti lórí ilé mi lọ́sẹ̀ yí, Olúwa yìí dànù, ní orúkọ Jésù
(2) Olúwa, pa mí mọ́ kúrò nínú gbogbo ìjàmbá lọ́sẹ̀ yí, ní orúkọ Jésù
(3) Gbogbo agbára tó ní mi ò ní rí ọ̀nà abayọ lọ́sẹ̀ yí, Olúwa fi iná run agbára bẹ́ẹ̀, ní orúkọ Jésù.
(4) Gbogbo ilẹ̀kùn tí àwọn alágbára òkùnkùn tì mọ́ mi, agbára Olúwa o, ó yá ṣíi fún mi lọ́sẹ̀ yí, ní orúkọ Jésù
(5) Ó jáde kò wọlé, kò ní jẹ́ ìpín mi tọmọ tọmọ lọ́sẹ̀ yí, ní orúkọ Jésù
Fún Adura +2347038982510
Ẹ jọ̀wọ́ ẹ share kí ẹ sì follow Prophet/Evang Onala Oluwasegun
Bí Olúwa bá fi sí yín lọ́kàn láti ran ìpè yí lọ́wọ́, 3054253157 Onala Clement Oluwasegun. Polaris Bank. Ẹ ò ní jẹ tàbí mọ ìkorò, ní orúkọ Jésù