TACN olorungbogo assm prayer forum

TACN olorungbogo assm  prayer forum olorungbogo assm prayer forum

13/01/2022

* Oluwa pa ami okunkun re lara mi ki awon olore ti o ran simi lodun yi le rimi kankan.
* Ohun rere gbogbo timo fi ilaagun ati aawe ati adura mi fa lodun tokoja towo mi o to oluwa Soo di irorun funmi lodun yo

01/01/2021

* Gbadura so fun oluwa gbogbo eni to dana ogun funmi ya lodun to lo ti mio fi ri ohun rere kan toka si ti odun naa fi lo to ti tun n mura ati dana ogun funmi lodun yi oluwa ina ogun ti o n da yi lee lori.
* Oluwa je ki n firorun lo odun yi ati emi ati ile mi
* Oluwa je tito mi ninu odun yi mase je ki n mo ikoro lori omo Lori aya ati lori ayee mi tikalara mi.
* Bi awon eniyan ba nsun ekun kikoro ninu odun yi fun aini ati iponju ti n bo wa ba gbogbo orile-ede oluwa nitori ti apa re n be lara mi ati ile mi mase je ki a bawon ni iriri re loruko Jesu
* Oluwa mase je ki alaanu ati oloore ati alatileyin ki o jina Simi ninu irin ajo odun na.

10th days of tacn olorungbogo assembly is continue.....today the annoitting of God's flow more than of yesterday come an...
11/12/2019

10th days of tacn olorungbogo assembly is continue.....today the annoitting of God's flow more than of yesterday come and experience the power of our Lord Jesus..where is was performing signs and wonderful....is the same yesterday today and forever more................

12/11/2019

PRAYER FOR THE WEEK
1* ofá atúnidá tí a ta sínú àgó mi ti o tun aye mi ro si ohun ti mio fe ati eyi ti iwo Olorun ko yan fúnmi Oluwa ti ofà na jáde lara mi ki aye mi kio gba àtúnse.
2* Ègún tó wà ninu iran mi to sise lori baba mi toti tun bere ise lori emi omo pèlú Oluwa nitori mo ti fi aye mi fun o je ki egun na o pare lori mi.
3* Olórun rin ìrìn-àjò de òpin ilè ati aye lati gba pada ohun timo sonu sowo awon okunkun Olorun gba funmi nitori mo ti fi aye mi funo patapata.
4* Ida tia gbe soke nibiti a gbe ti bimi fun ibi Oluwa je ki Ida na wale lofifo ki o mase jeun ninu ile mi jale osu yi ati jale odun yi.
5* Ikore opin odun ti awon okunkun nse lati kore fun opin odun Oluwa mase gba laaye kiwon o raye ninu ile mi.
6*Majele tia fun olore mi je ti iye re fi ra lati semi loore Oluwa fi eje re pa oro majele na kio le semi loore.
7*Eniti mo pe ni ebi timo pe ni ore sugbon ton fi ogun ja aye mi nikoko Oluwa fa a*o ya kuro lara re ki o si funmi nisegun lori re bi o ti fun modekai ni isegun lori hamani.
8* Gbogbo awon okan tiwon n se ipade nitori emi omo ologo, ipade ojule de ojule ipade onípòjipò bi o ti tu awon to n ko ile-iso babeli ka nigbnani oluwa tuwonka ki ipade gbogbo tia tise nitori mi le jasi asan.
9* Ayeraye gbami o ti funmi ni awon omo wonyi mase gba laaye ki n fi owo mi gbe omo sin ati aya ati oko bio tile je ipe egun ati epe ni pelu ninu iran mi.
10* Nitori oruko re Oluwa rami pada ra ile mi pada ajoyo tiwon pinu re ki o mase wa si imuse lori ile mi ki n le je ise na tio fi ranmi
11* Oluwa olore tiko ni salai je ise na tio ran simi Oluwa mu idiwo gbogbo kuro ni ona re kio le raye je ise tio ti ran simi ninu osu yi ati ninu odun na
🌿🌲🌴📘✝️🛐 Ki alaafia Olorun kio ma ba yin gbe ati gbogbo okan ti o ba se olotito si adura yi ti o si gbagbo ninu re pe adura lo ngba agbara ko iyanu yio sele loruko Jesu Christi Oluwa Amin ✝️

09/10/2019

1. Olorun jaa ilekun irin ti a*o Mo Iran mi ki emi omo ologo le koja. 2. Orisa ton gbebo ni ile baba mi ni otise nigbani jeki INA o bolu awon to mbo orisa na ati orisa na. 3. Aside ojo pipe togba irinajo ogo lese mi, olorun da pada fun mi. 4. Okun toso mi po Mo awon keferi tafi Jo korin kanna pe kosi, olorun ja okun na Lara mi ki nsi di omnira. 5. Anu fi Josefu han ni ile ajeji olorun jeki anu ofimi han losu yi ati ebi mi. 6. Emi airi to darapo Mo irinajo mi tosiwaju mi Lodo olore, Olorun da Lebi kosi gbadanu ninu ile mi lati oni lo. 7. Olorun olubukun toni kokoro ile Dafidi lowo bukun mi 3x tori Mo setan lati fi Oun INI mi sin o ki ota mi ole pehinda.

08/10/2019

Address

1. Legun Maidan Road Matogbun
Lagos

Telephone

08028113306

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when TACN olorungbogo assm prayer forum posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share