Cac Oke Anu Idimu HQ

Cac Oke Anu Idimu HQ Official page of CAC OKE ANU, IDIMU HQ. ONE FOLD, ONE SHEPHERD

22/01/2025

JOBU 38:12
[12]Iwọ paṣẹ fun owurọ lati igba ọjọ rẹ̀ wá, iwọ si mu ila-õrun mọ̀ ipo rẹ̀?
Hast thou commanded the morning since thy days; and caused the dayspring to know his place;

13/01/2025
ORIN DAFIDI 98:9[9]Niwaju Oluwa; nitori ti mbọwa iṣe idajọ aiye: pẹlu ododo ni yio fi ṣe idajọ aiye, ati awọn orilẹ-ède ...
03/01/2025

ORIN DAFIDI 98:9
[9]Niwaju Oluwa; nitori ti mbọwa iṣe idajọ aiye: pẹlu ododo ni yio fi ṣe idajọ aiye, ati awọn orilẹ-ède li aiṣègbe.
Before the LORD; for he cometh to judge the earth: with righteousness shall he judge the world, and the people with equity.
Good morning people of God,here is the word of the Lord for you and I this morning, and it turn it's self to a word from God for everyone who make it to be a living testimony this day because there is life in God's word,I humbly present the word of truth, that leads to eternity to us all,that we should watch our conduct and deed because he is coming to judge the world and the people with equity....the coming of Christ is near and it's expected of us to move close to him before he comes near to us.

30/12/2024

YOUR YEAR OF UNLIMITED BLESSING

THE LORD CARES
#2025

30/12/2024

DIUTARONOMI 11:12
[12]Ilẹ ti OLUWA Ọlọrun rẹ nṣe itọju; oju OLUWA Ọlọrun rẹ mbẹ lara rẹ̀ nigbagbogbo, lati ìbẹrẹ ọdún dé opin ọdún.
A land which the LORD thy God careth for: the eyes of the LORD thy God are always upon it, from the beginning of the year even unto the end of the year.
#2025 °°°•°°Says the lord•••°°°°°

30/12/2024

Join us at CAC OKE ANU IDIMU H/Q LAGOS NIGERIA.

30/12/2024

Yoruba Bible. DIUTARONOMI 11:11-14
[11]Ṣugbọn ilẹ na, nibiti ẹnyin nlọ lati gbà a, ilẹ òke ati afonifoji ni, ti o si nmu omi òjo ọrun:
But the land, whither ye go to possess it, is a land of hills and valleys, and drinketh water of the rain of heaven:
[12]Ilẹ ti OLUWA Ọlọrun rẹ nṣe itọju; oju OLUWA Ọlọrun rẹ mbẹ lara rẹ̀ nigbagbogbo, lati ìbẹrẹ ọdún dé opin ọdún.
A land which the LORD thy God careth for: the eyes of the LORD thy God are always upon it, from the beginning of the year even unto the end of the year.
[13]Yio si ṣe, bi ẹnyin ba fetisi ofin mi daradara, ti mo filelẹ li aṣẹ fun nyin li oni, lati ma fẹ́ OLUWA Ọlọrun nyin, ati lati ma sìn i pẹlu àiya nyin gbogbo, ati pẹlu ọkàn nyin gbogbo,
And it shall come to pass, if ye shall hearken diligently unto my commandments which I command you this day, to love the LORD your God, and to serve him with all your heart and with all your soul,
[14]Nigbana li emi o ma fun nyin li òjo ilẹ nyin li akokò rẹ̀, òjo akọ́rọ̀ ati òjo àrọkuro, ki iwọ ki o le ma kó ọkà rẹ, ati ọti-waini rẹ, ati oróro rẹ sinu ile.
That I will give you the rain of your land in his due season, the first rain and the latter rain, that thou mayest gather in thy corn, and thy wine, and thine oil.here is the word of God for us as we journey into the year 2025.....may is grace be for us beyond measure

REVIVAL REVIVAL REVIVAL!!!📣📣📣We cordially invite you to A 5 days revival tagged: “Let God Arise”It’s going to be power p...
21/04/2023

REVIVAL REVIVAL REVIVAL!!!📣📣📣

We cordially invite you to A 5 days revival tagged: “Let God Arise”

It’s going to be power packed and filled with breakthrough, salvation, deliverance and a lot of answering of prayers

Date: 24th to 28th April 2023.✅

Time: 6pm - 8pm✅

Invite all your friends and families to have a share in the grace of God!

It’s a new dawn; Don’t miss out!

Hallelujah.

Address

Lagos

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Cac Oke Anu Idimu HQ posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share