Cac Unique Glory of God

Cac Unique Glory of God Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Cac Unique Glory of God, Religious organisation, Fafolu Street Olorunsogo Mushin, Lagos.

19/02/2026

MO GBADURA BI WOLI OLORUN NIGBATI AKOKO BA TO LATI JE ISE TI O JISE-JIYA FUN NI OWURO OJO , IKU KO NI PA O. NI ORUKO JESU AMIN.

18/02/2026

Connect with God. Every Day.

16/02/2026
11/02/2026

Akori Eko:- AGBARA IHINRERE. Eko KiKa:-Romu 1:16. Agbara Ihinrere Jesu Kristi je Pataki ohun ti Olorun pe wa fun ninu aye yi , papa awa onigbagbo ti a ti gba Jesu Oluwa wa, o si je dandan funwa lati se bi o ti to ati bi o ti ye lai fi itiju se Nitori emi ko tiju ihinrere (Rom 1:16; 2Tim 1:18; 1Kor 1:8; Ise Apo 3:26) Jesu Kristi Oluwa wa fun wa ni ase lati lo waasu Ihinrere fun gbogbo eda alaye (Mark 16:15, Matt 28:18; Luk 24:47-48). Nipa eyi o tun se awon ohun ti a ma lo fi se ise na lase yori, opo awon Oniwaasu ode oni ti so awon ohun pataki na nu , eyi lo mu ki opolopo Oniwaasu ma wa agbara lo si odo awon elewe Omo loja tabi awon Adahunse Jesu Oluwa wa npe gbogbo eniyan pe ise po ni ogba ajara sugnon alagbase ko .to. E jeka ronu wa wo nitori Onnkan fere de lati wa siro ise wa,ti o ba si de, iwo Oniwaasu elewe Omo nibo ni yio ti bao? Eyi yo je itiju eniti ko ba gbagbo. Ayanfe , e lo mura. Jesu Oluwa wa fere de tan . Ki alafia Oluwa wa ati Ore -Ofe Re ma ba wa gbe wa t**i lae Amin.

31/01/2026

With Prophet Sam Olu Alo – I'm on a streak! I've been a top fan for 15 months in a row. 🎉

Address

Fafolu Street Olorunsogo Mushin
Lagos

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Cac Unique Glory of God posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Place Of Worship

Send a message to Cac Unique Glory of God:

Share