19/11/2023
REVIVAL HOUR OF TRINITY MINISTRIES ANNUAL 60DAYS FASTING AND PRAYER 2023
OSE KETA
Scripture reading : Exodus 3:1-17, John6:1-14
Prayer points
1. Dupe lowo Olorun orun ohun aye
2. Oluwa mu mi kuro labe ojoji iku ati iponju
3. Oluwa je ki ilekun ise ami ati ise iyanu ko si ninu aye mi
4. Gbogbo iboju tabi idiwo to demi lona lati wo inu ise iyanu mi Oluwa mi kuro lona mi
5. Kanga aye mi gba ifowo Olorun ki o si ma sun iyanu Olorun jade
6. Eje Jesu fo ayanmo mi mo ki ogo Olorun ko si wo inu ayanmo mi
7. Gbogbo agbele ipada seyin ati ijakule ni ninu aye mi e fo loruko Jesu
8. Ina Olorun alaye lo si ojo iwaju mi , oni mi ati ana mi ki o si se ise itusile to lagbara nibe loruko Jesu
9. Gbogbo a*o Ogun ti ile iya ti ile Baba lara mi jona loruko Jesu
10. Ile ala mi to to di Ile Ogun di Ile mimo loruko Jesu
11.Ile aye mi ti ko so eso bere si ni so eso loruko Jesu
12. Gbogbo egun , majemu ati Ogun irandiran ninu aye mi di p**a run loruko Jesu
13. Ounje mi ati iyanu mi a ko ni fi fun aja loruko Jesu
14. Gbogbo egun ati majemu ipada seyin laye mi e maa parun loruko Jesu
15. Gbogbo nnkan rere ti mo ko Jo esu ko ni parun loruko Jesu
16. Gbogbo ofa osi ati asan jade laye mi loruko Jesu
17. Gbogbo agbara to n fa agogo aye mi seyin ina Olorun alaye Jo run loruko Jesu
18. Ororo ore ofe, ayo ati akotun agbara ma San Lori mi loruko Jesu
19. Lati ori mi de atelese ororo itusile ma San ki o si se ise agbara loruko Jesu
20. Loruko Jesu emi yoo ma lo lati Inu okun de inu okun ati lati Inu agbara de inu agbara.
1,Thank you God of heaven and earth.
2,oh lord God bring me out of the shadow of death and affliction.
3,oh lord God let the doors of sign,wonder and miracle be opened unto me
4,All veils of darkness that is preventing from entering into miracles be destroyed in Jesus name.
5,well of my life receive the touch of Jesus and flow out miracle.
6,my destiny be purged by the blood and carry the glory of God in Jesus name.
7, Embargo of retrogression and failure break in Jesus name.
8,Hol