23/08/2026
Ó mà ṣe o😭😭
Mo gbàdúrà fún gbogbo ọwọ́ tó rí àmín ṣe, pé, májẹ̀mú tó fẹ́ pa ọ́ sọnù ní àkókò tó yẹ kí o máa jẹ èrè làálàá rẹ, kí májẹ̀mú bẹ́ẹ̀ gbiná🔥 sọnù lórí ayé rẹ, ní orúkọ Jésù.
Ọfà àìsàn tó lè gba ẹ̀mí rẹ sọnù lójijì, kò ní bà ọ́ tọmọtọmọ, ní orúkọ Jésù
Bí o ti n tẹ àmín to dẹ̀ share, ayé ò ní share ìròyìn ìbànújẹ́ nípa rẹ tàbí àwọn ọmọ rẹ, ní orúkọ Jésù