Prophet Adeniyi S David Omoalayo Lesekese

Prophet Adeniyi S David Omoalayo Lesekese Prophetic prayer

16/12/2021

ORIN DAFIDI 23:1-4
[1]OLUWA li Oluṣọ-agutan mi; emi kì yio ṣe alaini.
[2]O mu mi dubulẹ ninu papa-oko tutù; o mu mi lọ si iha omi didakẹ rọ́rọ́.
[3]O tù ọkàn mi lara; o mu mi lọ nipa ọ̀na ododo nitori orukọ rẹ̀.
[4]Nitõtọ, bi mo tilẹ nrìn larin afonifoji ojiji ikú, emi kì yio bẹ̀ru ibi kan; nitori ti Iwọ pẹlu mi; ọgọ rẹ ati ọpá rẹ nwọn ntù mi ninu.

10/12/2021

AISAYA 25:1
[1]OLUWA, iwọ li Ọlọrun mi; emi o gbe ọ ga, emi o yìn orukọ rẹ; nitori iwọ ti ṣe ohun iyanu; ìmọ igbani, ododo ati otitọ ni.

Address

1 Powerline College Road Command Ipaja
Lagos

Opening Hours

Monday 09:00 - 17:00
Tuesday 09:00 - 17:00
Wednesday 09:00 - 17:00
Thursday 09:00 - 17:00
Friday 09:00 - 17:00
Saturday 09:00 - 17:00
Sunday 09:00 - 17:00

Telephone

+2348106369001

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Prophet Adeniyi S David Omoalayo Lesekese posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Place Of Worship

Send a message to Prophet Adeniyi S David Omoalayo Lesekese:

Share