Ona abayo si ohun ari loju orun

Ona abayo si ohun ari loju orun Ala je atona si ohun ti oje inkan ikoko Moje omo yoruba tomon nipa isese awon baba nla wa

09/01/2022

Ahunfani wa fun eni keni toba fe fi ise kale lati ran awon omo yoruba lowo enikan kijuba afogun sinu ku kosi aye fun epe mi ooo boba timo pe ole fi inkan toni lowo kale lofe fi ogun re pamon

28/11/2021

Bi eyan bahungbe ti kosanra
Elo wa ori aparo ewa iyere die elo papo kewa da sinu epo pupa kemon fi paara koto pe ojo meje enina ati sanra

13/11/2021

Eku ojumo ninu ile
Seri awon iseda kan wa ti ogun kii sise lara wan odara tiru wan bale mon se sara pupo atipe
Awon irawo kan inbe ti wan kogbodo mon lo ise ti wan ba fi ose se bi irawo ina ogun ti wan bajo lowulo fun wan aoni wa aye asan ooo

Address

Odota Area
Ilorin

Telephone

+2347034590060

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ona abayo si ohun ari loju orun posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Place Of Worship

Send a message to Ona abayo si ohun ari loju orun:

Share