Enoch Ogunniyi

Enoch Ogunniyi Church

26/05/2025

OGOJI ODUN NI BABA FI GB'EBE,
KA LE GB'EGBE TO L'OGO YI DIDE,
OGOJI ODUN NI OMO FI B'EBE,
LATI D'EGBE SARAFU YI SILE

22/05/2025

ẸNI TÍ O NGBE NÍ ÌBÍ ÌKỌKỌ ỌGA ÒGO, YI O MÁ GBÉ ABẸ ÒJÌJI ELEDUMARE

20/05/2025

OORUN KI YI O PA WA NI IGBA OSAN, TABI ODUPA NIGBA OORU NI ORUKO JESU KRISTI

20/05/2025

ÌBÙKÚN NI FUN ẸNIKẸNI TI O FI OLUWA SE IGBEKELE RE

20/05/2025

OLORUN YI O MO ODI IGBALA YI WA KA NI ORUKO JESU KRISTI

20/05/2025

ALAGBARA AIYE KI O KIYESARA,
NITORI AGBARA MA NLO TI O BA DI AKOKO KAN..
RANTI GOLIATI NINU BIBELI..

20/05/2025

Olukuluku ni yi o ru aisedede tire

20/05/2025

YEYE WA YI O DI AYEYE NI ORUKO JESU KRISTI

20/05/2025

YARA LATI GBO, LORA LATI F'ESI

12/10/2023
12/10/2023

It shall be well with you in Jesus Mighty Name
🙏

01/10/2023

Eyin Oba ogo, On ni Olorun
Eyin Oba ogo, On ni Olorun
Yin fun 'se 'yanu ti o ti fihan
O wa pelu awon ero mimo l'ona
O si je imole won l'osan l'oru.

E yin Angel 'didan, lu duru wura
Ki gbogbo yin juba, t'e now oju re
Ni gbogbo 'joba re, b'aye ti nyi lo

Ise re y'o ma yin
Ise re y'o ma yin
Fi ibukun fun Oluwa okan mi.

E yin fun 'rapada ti gbogbo okan
E yin fun orisun imularada
Fun inu rere ati itoju re
Fun 'daniloju pe O ngbo adura,

E yin fun idanwo bi okun ife,
T'o nso wa po moa won ohun orun
Fun 'gbagbo ti n|”segun , 'reti ti ki sa
Fun ile ogo t'O ti pese fun wa.

Verse 1
Praise the king of Glory, He is God alone,
Praise Him for the wonders He to us hath shown;
For His promised presence, All the pilgrim way,
For the flaming pillar, And the cloud by day.
Chorus
Praise?. Him, shining angels,
Strike .? your harps of gold,
All .? His hosts adore Him,
Who .? His face behold;
Through .? His great dominion,
While .? the ages roll,
All His works shall praise Him (3ce)
Bless the Lord, my soul!

Verse 2
Praise Him for redemption, Free to every soul;
Praise Him for the Fountain That can make us whole;
For His gifts of kindness, And His loving care,
For the blest assurance, That He answers prayer.
Chorus
Praise ?. Him, shining angels,
Strike .? your harps of gold,
All .? His hosts adore Him,
Who .? His face behold;
Through .? His great dominion,
While .? the ages roll,
All His works shall praise Him (3ce)
Bless the Lord, my soul!

Verse 3
Praise Him for the trials, Sent as chords of love,
Binding us more closely, To the things above;
For the faith that conquers, Hope, that naught can dim,
For the land where loved ones, Gather unto Him.
Chorus
Praise ?. Him, shining angels,
Strike .? your harps of gold,
All .? His hosts adore Him,
Who .? His face behold;
Through .? His great dominion,
While .? the ages roll,
All His works shall praise Him (3ce)
Bless the Lord, my soul!

Address

Ilorin

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Enoch Ogunniyi posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share