The fire of souls' winner church of Christ

The fire of souls' winner church of Christ And he said unto them, Go ye into all the world, and preach the gospel to every creature. He the believeth and is baptized shall be saved.

Soul winning is what the Master has sent us to do.

19/06/2025

JESU NI ONA OTITO ATI IYE KOSI IGBALA LODO ELOMIRAN BIKOSE ODO JESU GBA SAYE RE LONI OLA LEPEJU

Baba omo abunba bi ogidan omo afiru namo bi dagba omo mafiru nami ara mi koya omo re Alhaji Taoreed Adedigba ati emi Pas...
14/06/2025

Baba omo abunba bi ogidan omo afiru namo bi dagba omo mafiru nami ara mi koya omo re Alhaji Taoreed Adedigba ati emi Pastor Adetona ati Alira lsilamia lsikilu selede lehin re awon omo omo SEKINATU SAMUEL AKIMU RUKAYATU ati AFA KABIRU selede lehin re ayo to fisile lawa sun reeeoooooo

lFIHAN 14-13 Mo si gbo ohun kan lati orun wa nwi fun mi pe kowe re Alabukun fun ni awon OKU ti oku nipa ti Oluwa lati ih...
14/06/2025

lFIHAN 14-13 Mo si gbo ohun kan lati orun wa nwi fun mi pe kowe re Alabukun fun ni awon OKU ti oku nipa ti Oluwa lati ihin lo Bee ni ni E wi ki won ki ole sinmi kuro ninu laalaa won nitori ise won nto won leyin*Oni lope 15/06/2025 lope 12years ti efiwa sile lo BABA mi ASAMU sun ree oo gbogbo awa omo re selede lehin re Ehin to fi sile ko baje o Numeri 23-12 Owe10*7Masun laya olorun re oo ASAMU sun reeee

27/05/2025
23/10/2024

Topic ODAJU ABIAMO Ekun jer 4:3 jobu 39:16 soro lori awon odaju abiamo iwo na ka oro olorun wonyi ki ole mo ona bi osr gba adura Genasisi27 1-44 tun gba oro ro Rakeli da ese ole ofe gbe le ori omo re abigbehin Genasisi 35-16-21 ) l Kronika 4:9_10 ti obale ka oro olorun yi oyeki iye re si bayi )Adura) JESU 1time EMI MiMO 3times Oluwa gbami lowo odaju abiamo tofi ogo sofo 2 Jesu gbami lowo odaju iya mi eje mi tofi ogo ta tete 3Jesu Aje odaju toni mio ni ri igba rere lo eyin alapata oruno ebami pin ara re eyo apa soto ese soto ori re soto ifun re soto ebami pa danu ni oruko JESU amin

14/11/2023
14/11/2023

Address

Ikorodu

Telephone

+2348034238209

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when The fire of souls' winner church of Christ posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share