Kingdom Against Kingdom

Kingdom Against Kingdom Cherubim and seraphim unification church of the lord. aladura world wide

28/12/2019
21/10/2019
a wa legbe, omo ogun igbaale, ti kerubu serafu, holy Michael balogun, dide fun iranwo, a wa nbe JESU kofun wa laaye lati...
29/09/2019

a wa legbe, omo ogun igbaale, ti kerubu serafu, holy Michael balogun, dide fun iranwo, a wa nbe JESU kofun wa laaye lati ba esu ja, ao si segun, ka le gbe oruko. salvation army anthem. mogba adura fun gbogbo eniyan ti o ri amin nla kan se pe, bi oti le wu ki ogun aye re je akinkanju to, mofi ase ojo ajudun holy michael oni soro pe, ogun aye re ida orun ko run won danu, ida holy michael ko pa won run, agbara to fi eto igbega re sinu ahamo, ina emi mimo ko jo won run, ekiyesi eyin eniyan, oni ina siwaju OLUWA o si jo awon ota re run, mo so oro ase tele, gbogbo ogun to ni o ni ni testimony ayo, oya orun pa won run, e kiyesi ninu iwe luku 19:27 oni gbogbo awon ti won ko fe ki emi ko joba lori won, o ni e kowon wa si iwaju mi ki e si pawon, e gbo iwo ti oba le se amin to ni ina ninu, gbogbo ota ile, ota ode, amoni seni, aseni bani daaro, eyi ro lodi si igbega re, ida orun se awari won, owun ti mo so re gege bi woli ati iko iriju olorun, O ya ase irorun kowonu aye re be, ni ibi ti a ti ko o sile, oya lo pase lori won, o ya e bere sini se rere, oti dara fun yin, ase irorun ko wonu aye yin, connection ti enikankan ko lo ri ni idile iya ati baba, orun fi fun yin, e wonu ogo lo, oti ri be, ni ase ti baba, ri omo ati emi mimo, JESU OLUWA, AMIN AMIN AMIN NI ORUKO JESU,

Advice is a stranger, if he s welcome he stays for d night, if not he leaves d  same day. Good morning my brothers and s...
25/09/2019

Advice is a stranger, if he s welcome he stays for d night, if not he leaves d same day. Good morning my brothers and sisters in s lord

29/05/2019

Oluwa sanu mi ooo, Olorun sanu mi oo, awon ti mo foro lo yeye mi lonse. Mo gbadura fun e ni osan yi, kk osu may yi to pari Orun da si oro aye re . Larin awon otosi Orun fa e yo kuro. Oya bere sini se rere. Iwo leri kan

E fi ope fun Oluwa, nitori ti o seun, nitori anu re duro lailai, je ki aeon eni irapada Oluwa ki o with bee, eni ti o ra...
20/02/2019

E fi ope fun Oluwa, nitori ti o seun, nitori anu re duro lailai, je ki aeon eni irapada Oluwa ki o with bee, eni ti o rapada koro lowo ota nni, o si ko won jo lati ile won nni wa, lati ila oorun wa, ati lati iwo oorun, lati ariwa ati lati gusu wa, won n rin ka kiri ni aginju nibi ti ona ko si, won ko ri ilu lati maa gbe, ebi npa won, ongbe si ngbe won, o re okan won ninu won, nigba na ni won kigbe pe Oluwa ninu iponju won, o si yo won kuro ninu ise won, o si mu won jade nipa ona tito, ki won ki o le lo si ilu ti won yio ma gbe, eniyan iba ma yin Oluwa nitori oore re, ati nitori ise iyanu re si awon omo eniyan, nitori ti o te IFE okan ti ngbe ngbe Oorun, o si fi ire kun okan ti ebi npa, iru awon ti o joko ni okunkun ati ni ojiji iku, ti a de ninu iponju ati ninu irin, nitori ti won se ite si oro Olorun, won si gan imo oga ogo, nitori naa o fi laalaa re okan won sile, won subu, kosi si oluranlowo, nigba na ni won kigbe pe Oluwa nibi iponju won, o si gba won ninu ise won, o mu won jade kuro ninu okunkun ati ojiji iku, o si fa ide won ja, eniyan iba maa yin Oluwa nitori loore re, ati nitor ise iyanu re si awon omo eniyan, nitori ti o fo ilekun ide won nni, o si kee opa idabu irin won nni si meji, adiwere nitori irekoja won, ati nitori ese won, oju npon won, okan won ko ounje kounje, won si sun mo eti enu ona iku, nigba na ni won kigbe pe Oluwa ninu iponju won, o si gba won ninu ise won, o ran oro re, o si mu won lara da, o si gba won kuro ninu iparun won, eniyan i ba ma yin Oluwa nitori oore re, ati nitori ise iyanu re si awon omo eniyan. Psalm 107. Mo gba adura fun ni oni owuro yi, Oluwa yio yara lati ran e lowo. Yio gbe alanu dide si e.

20/02/2019

E kiyesi, o ni, nitori sioni emi ki yoo dake, ati nitori Jerusalemu emi ki yoo sinmi, t**i ododo re yoo fi jade bi titan imole, mo gbadura fun gbogbo okan ti o na le te amin kan, fire kan ati confirm kan si abe post yi pe, nitori oro aye re, Olorun ko ni dake mo, nitori Oro aye re, Olorun ko ni sinmi mo, yio se ti e lase pe, enu egan taye fi ngan e, orun sodi ogo, isele igbe dide re ko sele kia kia. Wa ni testimony ayo. Oti ti be, Ni ase ti BABA, ti OMO ati EMI MIMO. JESU OLUWA WA. AMIN, FIRE, CONFIRM

Address

Ikeja

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Kingdom Against Kingdom posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share