Egbe Isegun, Imole DE, Ala Funfun Gbo

Egbe Isegun, Imole DE, Ala Funfun Gbo Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Egbe Isegun, Imole DE, Ala Funfun Gbo, Religious organisation, No 48 molipa Road, opp four number house IJEBU ode, Ijebu Ode.

12/01/2022

IPADE EGBE ISEGUN IMOLE DE ALAFUNFUN GBO YIO WAYE LOLA ALAMISI THURSDAY (13/01/2022) NI ILE YEYE OBA ISEGUN WA TO WA NI ILU IMODI IMOSAN AGOGO MEWA OWURO (10.AM) NI IPADE YIO BERE O SI SE PATAKI KI ESE GBOGBO OMO EGBE PE SI IPADE NA, E SE PUPO, EWE ATI EGBO A MA JE WA NI ISE IRE OO (ASE)

11/07/2021

OMUSA ISEGUN.... IPADE EGBE ISEGUN IMOLE DE ALAFUNFUN GBO YIO WAYE NI TH.URSDAY OSE YI NI ILE EGBE WA TO WA NI MOLIPA ROAD OPPOSITE 4 NUMBER HOUSE IJEBU ODE

01/01/2020

A FI ASIKO YI KI GBOGBO AWON OMO EGBE IMOLE DE ALAFUNFUN GBO PE WON KU AYEYE ODUN TUNTUN TI ASESE BO SI A GBA DURA PE NINU ODUN TUNTUN YII ILE A KO GBE, ILE A KO RIN OWO ATI ALAFIA ARA NI OLORUN YIO FI TAWA LORE LEKANSI A KI YIN PE E KU ODUN E SI KU IYE DUN EMI GBOGBO WA YIO SE OPOLOPO ODUN LAYE PELU ALAFIA ARA

07/12/2019

A FI ASIKO YIN KI DR TUNDE OGIN FUN TI ODUN IFA TI WON SE LONI OJO KEJE OSU KEJILA ODUN YIN (07/12/2019) NI SABO MOLODE IJEBU ODE EYIN TESE TODUN YI LE MA SE TODU TO NBO LASE EDUMARE

29/11/2019

MO FI ASIKO YI KI OBA ISEGUN DR AGBONGBON OLAMIJI PELU GBOGBO AWON OLOYE EGBE ATI AWON OMO PE WON KU IPALEMO ODUN TO NBO LONA

26/11/2019
10/11/2019

A FI ASIKO YI KI YEYE OBA EGBE ISEGUN IMOLE DE Egbe Egbe Isegun, Imole DE, Ala Funfun GboEgbe Isegun, Imole DE, Ala Funfun Gbo Imole Egbe Isegun, Imole DE, Ala Funfun GboEgbe Isegun, Imole DE, Ala Funfun Gbo Ala Funfun Gbo CHIEF DR MRS OMITOGUN OLAWUNMI KU AYEYE ODUN ORISA TI WON SE ASEYI SAMODUN

08/11/2019

IWE ASINA AO JA EWE IYALOSDE AO GBO PELU OMO IWE AO YO AWON SAKASAKA RE KURO AO LO FI WE PELU OSE SODA ATI KANKAN TUNTUN

02/11/2019

GBOGBO OMO EGBE IMOLEDE ALAFUNFUN GBO FI ASIKO YI KI CHIEF DR JEWO FUN TI ODUN EEGUGUN ABEYEFO TI ILU ATAN IJEBU EMI A SE OPO ODUN LAYE( ASEE)

Address

No 48 Molipa Road, Opp Four Number House IJEBU Ode
Ijebu Ode

Opening Hours

10:00 - 16:00

Telephone

+2347050673905

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Egbe Isegun, Imole DE, Ala Funfun Gbo posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share