Paul Gospel TV

Paul Gospel TV Spirit Sermon, Music

31/08/2024

゚viralシ2024fyp #

31/08/2024

゚viralシfypシ゚viralシalシ

30/08/2024

Jesus okay Omo Jairu dide

30/08/2024

゚viralシfypシ゚viralシalシ

29/08/2024

What's your take on this?

29/08/2024

Jésù wo ẹni tí wọ́n bí ní afọ́jú sàn
Jòhánù 9:1-12.

Bí Jésù ti ń kọjá lọ, ó rí ọkùnrin kan tí ó fọ́jú láti ìgbà ìbí. Àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ sì béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé: ‘Rábì, ta ni ó ṣẹ̀, ọkùnrin yìí ni tàbí àwọn òbí rẹ̀, tí a fi bí i ní afọ́jú?

Ìdáhùn Jésù jẹ́ èyí tó lani lóye dáadáa, Kì í ṣe ọkùnrin yìí ni ó ṣẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni kì í ṣe àwọn òbí rẹ̀,

ọ̀nà ìyanu táa fi la ojú ọkùnrin afọ́jú náà ṣiṣẹ́ fún fífi iṣẹ́ Ọlọ́run hàn, Bíi ti ọ̀pọ̀ àwọn mìíràn tí Jésù mú lára dá, irú iṣẹ́ bẹ́ẹ̀ fi ìfẹ́ àtọkànwá tí Ọlọ́run ní fún ìran ènìyàn tó ń jìyà hàn,

ó sì tún fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé a lè gbẹ́kẹ̀ lé ìlérí Rẹ̀ láti mú gbogbo àìsàn àti ìyà ẹ̀dá ènìyàn wá sópin ní àkókò tí ó tọ́ lójú Rẹ̀. Aísáyà 33:24.

28/08/2024
28/08/2024

Baptism turns wrestling

Address

Makalewo Street
Ijebu Ode

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Paul Gospel TV posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share