18/10/2025
KINNI NTI ANPENI ALALILA
ALALILA JE...
Oun ami, apere ati akiyesi ti aofimape aiye pe meji, aye ni koro, aye kenu aye porisirisi... Oun ni aofima pe emi amajade lara, nitori pe emi kisun nitie, emi ama sinmi ni, gbogbo inti akoleri nigba tiabawa laye tiayajule, tosepe akole durowo iru nkan be ni aleri ni oju alawa gegebi akoleri alujonnu, iwin, emere, oku pelu awon emi airi toku laikisepe awa loju orun, gegebe nani akoleri arawa ayafi tiabawo digi (glass mirror) loku.....sugbon nioju alawa anfaniwa latileri arawa gegebi gba tianwo film... fun itosona, itaniji ati ipen*si akiyesi ni irufe awon ala man sabaje..
AWON KAYEFI TIOWA FUN ALALILA........
Awon Kayefi Tiowa Fun Alalila... kayefi tiobami leruju nipe emiwa tiafimi nani yio jade kuro losi aye keji tiamosi oju ala, totumosipe oku niwa tiabati suntan, sugbon kioromile yeo dada, sebi omawipe oku amari oku egbere, oku ama barawon soro, asima waye loju ala kieniyan ori oku kodagan okuyen lemaba enina soro. apere nu tiaofima pe oku niwa tiabatisun tan tori oku nani oni afani atiri oku egbere.....
sugbon iyato tiowa laarin iku ati orun niwipe bieniyan batiku orun ni onitowun nlo, sugbon bieniyan basun agbede meji aiye oun orun ni emina yio durosi, tiobawu adeda aniki eniyan osun kiotoju orun bosi ojuku, sugbon lopolopo igba tiabasun amasaba ji ni, nitori emina yio sunma aiye pupo dada tiaba sun, sugbon gbogbo ntikole sele nigba tiawa lori eepe laye, nio man sele tiabasun tan nitori alalila kunfun opolopo kayefi, arisema, awoyanu, akotagiri, kiki iberu ati iriran oniranran tioju kieniyan osope ounweju lo......
apeere biki aripe eniyan dimeji meta tabi pupo abi kosepe eniyan nrin loju ofurufu, abi kosepe eniyan nrin lori agbalalubu omi, abi kosepe eniyan nrin ninu ina tiba kani gbogbo aiye fun ralarare dorikodo, leleyi tiosepe kole sele laye tiawayi, nje iwo woyesi asiko tiabasun tiabajitan, wakati yiowu tiabafisun yen boya wakati mejo (8 hours) tabi jubelo, kodagan otunlema tobe, iye wakati tiobawu kiafisun tia bajitan awada iseju meji tabi kanipe bi ogban iseju niakan fisun, eleyi lotokasipe isemi tialoni orun oju eleyi tiabalo layelo biotilewu kiape layeto...
EMIKEJI TIONISE PELU ITANIJI ATI ITOSONA....
Huumn!!! alalila tabi kianipe emikeji tionise pelu emi airi tiokunfun kiki kayefi ati ikilo, itaniji, itosona, ati fun orisiri iranti ounti otipe tiosepe akole funrawa ranti man, atifun igbaradi fun oun tofesele, lafikum alalila kunfun kiki kayefi, arisema, awoyanu, akotagiri, kiki iberu ati iriran oniranran tioju kieniyan osope ounweju lo... elomiran tiobasun lojualare onitohun yioma wipe alani ounla kodagan yiotun sope alani monla yiotun pinnu pe oun kotifeji boya ala tionitohun nla ala tiodunmo ni alana, ti osima sope kotiwu ohun kiohun ji tabi kiohun file maji saye man, nitoripe alationla dunman ni, tiobasije ala iberu nionitohun nla, yio mapariwo pe kiwonji oun alani oun nla, nitorepe alanaje kiki iberu akotagiri fun onitohun, pelu eretete iberu tioniagbara ni oluware yio baji loju orun.
Opolopo eniyan lo ma nla ala sungbon kokin ranti ma tobatiji.. Elomiran kotie ni la alagidi debi tiomase anfani fun..
Ti awon ota basetan lati da irin ajo aiye eniyan ru.. Won koni jeki oranti gbogbo ala toba la ma, tori wonma pe itosona ni ala je fun eniyan toba ni ebun yen, aiye ama gba ebun ala Lara eniyan , koni ri nkankan ma loju orun koda oletun mala alakala loju orun....
AINI IKANKUN LORI ALA TIENIYAN BANLA.....
Eniti olohun ba fun ni ebun ala olohun ti fun ni idaji iriran, nkan ti ala fi se pataki nipe itosona ni ala je ninu aiye eda.. ala kose fi sere rara nitori pe ala ama soro nipa nkan tin sele lowo lowo ninu irin ajo aiye eda,ala asitun ma soro ni pa nkan ti yio pada ma sele ni ojo iwaju....
ala atun ma soro ni pa nkan ti oti sele si eyin ninu irin ajo aiye elomiran, oju ala ni oye ki elomiran tiri ona Abayo si isoro aiye re sungbon aika ala kun re ni koti jeki elomiran tiri ona abayo si oro aiye re..
alakala ama fa aisan ati aini ifokanbale sinu aiye eniyan toba ma nla alakala..
ti aiye bafe gbe aburu tabi ofa sinu ara eniyan, won ama gba ipase alakala wole si eniyan lara..
nipa ki eniyan majeun loju orun... asasi ati ofa ni awon ota ma fi iru awon ala yi gbe si eniyan lara..
alakala ama mu ifaseyin woni aiye eniyan to ba nsaba la alakala......
ki olohun gbawa lowo ogun aiye nih.. amin...
FUN IWADI AKOSEJAIYE RE LATI MA IRU OGUN TO NJA O NINU IRIN AJO AIYE RE ATI ONA ABAYO... WHATSAPP 08115897221
like, comment and share...