11/05/2026
THE VOICE........Ezra 9:9
[9]Nitoripe ẹrú li awa iṣe; ṣugbọn Ọlọrun wa kò kọ̀ wa silẹ li oko ẹrú wa, ṣugbọn o ti nawọ́ ãnu rẹ̀ si wa li oju awọn ọba Persia, lati tun mu wa yè, lati gbe ile Ọlọrun wa duro, ati lati tun ahoro rẹ̀ ṣe, ati lati fi odi kan fun wa ni Juda, ati ni Jerusalemu.
For we were bondmen; yet our God hath not forsaken us in our bo***ge, but hath extended mercy unto us in the sight of the kings of Persia, to give us a reviving, to set up the house of our God, and to repair the desolations thereof, and to give us a wall in Judah and in Jerusalem....... Beloved the Lord has not forsaken you in all your struggle, in this new week,you shall be granted mercy in the sights of kings and favour shall work on your accounts in the mighty name of JESUS....