Prophet Atilade Joshua Itedo Anu global page

Prophet Atilade Joshua Itedo Anu global page Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Prophet Atilade Joshua Itedo Anu global page, Evangelical church, IBADAN, Ibadan.

26/08/2026

Aanu oluwa yo dide fun oo oluwa gba Aye re lowo igbekun Ipọnju irunlowo olorun dide fun oo ni oruko Jesu

24/08/2026

Gbogbo eni to ba ro Iku ro Iwo ati Ile re, Angẹli iku mafi Ile re se ìbùgbé Ni Oruko Jésù kristi 🙏🙏🙏

22/08/2026

Any mistake you have made that closed the door of favour in your life, by the mercy of God, let that door be open now.
🙏

21/08/2026

ni oruko Jesu E lo pade Aanu ti yo run Aye yi lowo. IRANLOWO OJIJI YIO JADE SINU AYE RE L'ONI L'ORUKO JESU KRISTI 🙏🙏🙏

Ní òwúrọ̀ yìí, àṣẹ jáde sí ọ pé; Àánú máa tún ìtàn ayé rẹ kọ... Ọlọ́run Fúnraa'rẹ̀ yóò súré fún wa...Lábẹ́ bí ó ti wù kí...
19/08/2026

Ní òwúrọ̀ yìí, àṣẹ jáde sí ọ pé; Àánú máa tún ìtàn ayé rẹ kọ... Ọlọ́run Fúnraa'rẹ̀ yóò súré fún wa...
Lábẹ́ bí ó ti wù kí ó rí; A máa sọ ọ́ ní Orúkọ títún èyí tí ó ní ògo àti ìbùkún nínú.., a kì yóò pè ọ́ ní ìkọ̀sílẹ̀ mọ́ ní Orúkọ Jésù Kristi.

Ìyọ́nú Ọlọ́run kò ní kúrò lórí ayé wa. Níbi tí agbára wa kò bá tó, ìyọ́nú Rẹ̀ yóò gbé wa dé. Níbi tí ènìyàn bá ti kọ̀ wa...
18/08/2026

Ìyọ́nú Ọlọ́run kò ní kúrò lórí ayé wa. Níbi tí agbára wa kò bá tó, ìyọ́nú Rẹ̀ yóò gbé wa dé.
Níbi tí ènìyàn bá ti kọ̀ wa sílẹ̀, àánú Ọlọ́run yóò ṣí ilẹ̀kùn fún wa. Lónìí, ìyọ́nú Ọlọ́run yóò sọ ìtàn wa di ẹ̀rí, lórúkọ Jésù. Àmín.

17/08/2026

Ninu o se tuntun yi E lori anu ati ojurere pelu iranlowo atokewa gba loruko Jesu amin

16/08/2026

Gbogbo ami (mark) aseti ninu isẹda mi, Oluwa fi ẹjẹ Jesu parẹ.
2. Oluwa jẹki idaamu o dopin ninu gbogbo idawole mi lati oni lọ.

14/08/2026

Koto ti ota re gbe sile fun ra won ni yio Jin si,imoran Ota Koni Jo lori aye re,Ogun ateyinja Koni ja o

Address

IBADAN
Ibadan

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Prophet Atilade Joshua Itedo Anu global page posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share