27/01/2024
*Let us thank God for the nation*
Lori Rice, #2400,baba gba ope wa
Lori ewa, #1900,baba gba iyin wa
Lori isu #3300, Oluwa gba iyin wa
Lori purewater #250,Oluwa gba ope wa
Lori alaran kan,1700,baba gba ope wa
Lori sawa kan, #800,Oluwa gba ope wa
Lori kote kan #1900,Oluwa gba iyin wa
Lori kilo chicken,3600,Oluwa gba ope wa
Lori kilo turkey,4200,Oluwa gba ope wa
Lori Coke onigo #250,Oluwa gba ope wa
Lori Coke plastic #300,Oluwa gba iyin wa.
Lori bottled water #150, Oluwa gba iyin
Fun ipamora ati suuru ti e fun wa,Oluwa gba iyin wa...
Ni gbogbo ona,ee seeeeeee
Ni gbogbo ona,e se ooooo baba
Amin.