Itumo Ala Pelu Adura Isegun Tio Ye

Itumo Ala Pelu Adura Isegun Tio Ye This group is made to assist people with prayer when needed , and to find meaning and solution to our dreams with God direction

---------- AGBARA ALA --------    Ala ni agboti oba la ninu tubu , ti o fi pada si aafin pharaoh  ,Mo gbadura fun yin ge...
23/01/2026

---------- AGBARA ALA --------
Ala ni agboti oba la ninu tubu , ti o fi pada si aafin pharaoh ,

Mo gbadura fun yin gege bii woli Olorun alaye, wipe Ala ati iran rere ti yio mu yin de ibi giga ma se fun yin loruko JESU

06/11/2025

I thank God for the successful of my church anniversary.

04/09/2025

PRAISE GOD , WITH A
VERY BIG HALELUYAH ?

_____ORO AGBA____OHUN TII TAN  LODUN  EEGUN , OMO ALAGBAA  YOO  RA AKARA     JE  EKO  ? ?Ore wa Baye ba nyeo loni e je k...
09/06/2025

_____ORO AGBA____
OHUN TII TAN LODUN EEGUN , OMO ALAGBAA YOO RA AKARA
JE EKO ? ?

Ore wa Baye ba nyeo loni e je ka rora se Nitori Aye ki se tenikan , Beeni Aye ko si duro de Eni kan

Use your Time well Because no one knows what Tomorrow Will be ..

______ORO AGBA_____ E NI T'AA SE LOO RE TI KO DUPE , O DA BII OLOSA TO KONI LERU LO , NI . Arakunrin ati Ara binrin  E j...
07/06/2025

______ORO AGBA_____
E NI T'AA SE LOO RE TI KO DUPE , O DA BII OLOSA TO KONI LERU LO , NI .
Arakunrin ati Ara binrin E je ki a je Eni ti yio ma dupe bi o ti wú ki oore ti a ri gba o kere to .
Eni ti o ba dupe oore Ana odamiloju pe yio ri ominran gba.
Se. Mo. Wii. Re O .
( 081 64 37 04 50 ) Prophet TEMITOPE OPAALADE .

14/04/2025

HAPPY HOLLY WEEK.
EVERYONE.
May God almighty bless us
This week , to experience joyful EASTER

08/04/2025

ADURA OWURO
Bi e ba lese Amin nla, mogbadura fun yin gege bii Woli wipe.
Ofa asoni di Alaimoose , Koni bayin loruko Jesu

08/04/2025

ADURA OWURO
Loni OWURO kutukutu ojo isegun.
Mogbadura fun yin gege bii Woli wipe
Iran ati ala buburu ko ni se mo yin Lara

ADURA OWURO :  Olorun fi kaini gegun Nitori wipe o pa Abeli arakunrin re . (2) Jona ni Olorun nbinu si Nitori aigboran ,...
21/03/2025

ADURA OWURO : Olorun fi kaini gegun Nitori wipe o pa Abeli arakunrin re .
(2) Jona ni Olorun nbinu si Nitori aigboran , sugbon awon ti Jonna ba rin irin Ajo ni won farapa.
ADURA - Ao ni ba Eni ti o ti fi Ori gba Egun Olorun rin loni
Gbogbo Eni ti a le barin ,ti Olorun fi le ninu Siwa , Ao ni barin loruko Jesu olugbala .

17/03/2025

Ase ti Olorun fi da Ile aye ati orun ,
Yio pe Ohun rere jade fun yin loni.

______AJORO______Topic : Ninu igbeyawo . Sub topic : Eni Koko e ye  ni o mo lo. Ibeere :  Nje  se  looto ni wipe Eni ti ...
04/02/2025

______AJORO______
Topic : Ninu igbeyawo .
Sub topic : Eni Koko e ye ni o mo lo.

Ibeere : Nje se looto ni wipe Eni ti Koko re Baye ni o mo o lo ? , abi Ori ni afi n mu eran ninu awo , ?? Koni erongba tiyin ??.

02/02/2025

All Glory belongs to Almighty God
In Heaven.
HALLELUYAH.

Happy New month

Address

Ibadan

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Itumo Ala Pelu Adura Isegun Tio Ye posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Place Of Worship

Send a message to Itumo Ala Pelu Adura Isegun Tio Ye:

Share