Redemption prayer GROUP

Redemption prayer GROUP Amunda ojere along ojoo express road opp.CAC oka AYO Ori ade area Ibadan...

I PRAY FOR WHOEVER THAT TYPE AMEN HERE,BY NEST YEAR MY GOD WILL TURN ALL YOUR PRAYER TO POINT TO TESTIMONY IN JESUS NAME...
25/12/2019

I PRAY FOR WHOEVER THAT TYPE AMEN HERE,
BY NEST YEAR MY GOD WILL TURN ALL YOUR PRAYER TO POINT TO TESTIMONY IN JESUS NAME..

IWO NI KI ORI PE O SE AMIN,MO RI NINU ISELE ALAGBARA TI O SELE SI AWON OMO ISRAEL NIWAJU FARAHO,EMI O MON PE OKUN O GBUD...
19/12/2019

IWO NI KI ORI PE O SE AMIN,
MO RI NINU ISELE ALAGBARA TI O SELE SI AWON OMO ISRAEL NIWAJU FARAHO,EMI O MON PE OKUN O GBUDO SI LASAN,LA FI AWON KAN SE ETUTU,
HAMANI TI PINU FUN MODEKAI ,
BENI OLORUN NAN TI PINU RE FUN
AS BI ENIKAN BA MA DIDE ENI NI YIO FI ARA RE SE OHUN ETUTU,
(2) MO GBA ADURA FUN O LONI YI OTA IRE RE DI ETUTU FUN IGBE DIDE RE LONI N'ORUKO JESU,
2)MO WI LONI OHUN GBOGBO TI O PE NI OGUN AYE RE LONI DE ATEGUN RE LONI ,
(2)LATI ONIYI LO GBOGBO ENI TI O JA EMI ATI IWO NI OLE OGO ORUN MUN WON PA LOKOKAN
N'ORUKO JESU.
OHUN

ORO OLORUN WIPE,NI IGBA TI A DA IKOLO SIONI PADA WON DA BI ENI TI LA ALA,LONI OHUN GBOGBO TI OGUN TI GBA LO LAYE EMI ATI...
18/12/2019

ORO OLORUN WIPE,
NI IGBA TI A DA IKOLO SIONI PADA WON DA BI ENI TI LA ALA,
LONI OHUN GBOGBO TI OGUN TI GBA LO LAYE EMI ATI IWO ORUN DA WON PADA
N'ORUKO JESU.....

MI O MON OHUN TI O LE MA SE LOWO BAYI,SUGBON MO WI BI WOLI PE LONI OPIN DE BA OGUN AYE RE NI ORUKO JESU..BI ANAN DI ITAN...
11/12/2019

MI O MON OHUN TI O LE MA SE LOWO BAYI,
SUGBON MO WI BI WOLI PE LONI OPIN DE BA OGUN AYE RE NI ORUKO JESU..
BI ANAN DI ITAN OGUN AYE RE DI ITAN NI ORUKO JESU.
OJO ONI YI SI MA DE OPIN OWO AGBARA OLORUN FI OPIN SI OGUN AYE RE LONI
N'ORUKO JESU..

MO WI GEGE BI WOLI OLORUN LONI,BI OLORUN BA SI UN GBO TI AWO WOLI R,TI WOLI OLORUN BA SI KU LAYE LOTO,LONI LONI LONI,ORU...
11/12/2019

MO WI GEGE BI WOLI OLORUN LONI,
BI OLORUN BA SI UN GBO TI AWO WOLI R,
TI WOLI OLORUN BA SI KU LAYE LOTO,
LONI LONI LONI,ORUN IRANLOWO PELU IGBE DIDE SI FUN GBOGBO ENI TI O SE AMIN YI TI O SHARE ADURA YI
N'ORUKO JESU....

Address

Ojoo Express Road Amuda Ojere Iwo Road Area Ibadan
Ibadan

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Redemption prayer GROUP posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share