Islamic Sermon

Islamic Sermon Enlightening people about the word of Almighty Allah

05/01/2026

Suuru kii poo ju a e to re ni ko dara . Ti Eda be le se suuru lasiko ibinu yo pada de ibi ti orire Re wa .Alfa. Ipapo oloro bi. Imoran. .

18/12/2025

Ododo oro bi omo'ya isokuso . Oro re e o E jeki A gbo ki A si mu u lo. Alfa Ipapo oloro bi Imoran .

Pe iwo Aladugbo ati Alabagbe Re fun won nitori pe awa Eniyan A o ma je ainfani lara ara wa ni Olohun fi to wa po . Anabi...
13/12/2025

Pe iwo Aladugbo ati Alabagbe Re fun won nitori pe awa Eniyan A o ma je ainfani lara ara wa ni Olohun fi to wa po . Anabi (SAW) wa pewa si akiye si . Alfa Ipapo Oloro bi Imoran

THE IMPORTANCE OF NEIGHBOUR'S RIGHTS
Aishah and also Abdullah ibn Umar narrated that Rasulullah (SAW) said : "Archangel Jibrael kept on exhorting me about the rights of neighbours until I felt that they would be included in the category of heirs " (Bukhari , Muslim)
Archangel Jibrael was the one who used to bring Allah's revelation to the prophet . So whatever Jibrael said to him concerning neighbours was a revelation from Almighty Allah . It appears from the Hadith the importance of neighbours rights .
And also Abu Hurairah narrated that Rasulullahi (SAW) Said : "He who believe in Allah and the last Day must not put his neighbour to inconvenience , and he who believes in Allah and last Day must speak beneficently or keep quiet "
Abdullah ibn Umar reported that Rasulullah (SAW) Said: "The best companion in the sight of Allah is the one who is the best among all others to his companions, And the best neighbour in the sight of Allah is the one who is the best among all others to his neighbours "
Toju Alabagbe ati Aladugbo Re lai koni wo ti Esin , Eya ati Ede se daada si won ki Olohun le se daada si iwo na . Alfa Ipapo Oloro bi Imoran .

MASE  FI ONI GBAGBE ANA , RETI AWON ALAJOSE ANA KI O TO DI ONI TI O DARA FUN E KI O RAN AWON ENI ANA LOWO .  FARA BALE K...
05/12/2025

MASE FI ONI GBAGBE ANA , RETI AWON ALAJOSE ANA KI O TO DI ONI TI O DARA FUN E KI O RAN AWON ENI ANA LOWO .
FARA BALE KA ITAN PRESIDENT TRAORE PELU OHUN TO SE FUN ALAJO SE RE ANA KI IWO NA LE TIBE SORIRE .
( ALFA IPAPO OLORO BI IMORAN )

It was a bright afternoon in Wagadugu, the capital city of Burkina Faso. President Ibrahim Traoré had just finished a surprise visit to a local school. As he was heading back to the presidential convoy, something caught his attention.

THE IMPORTANCE OF NEIGHBOUR'S RIGHTS Aishah and also Abdullah ibn Umar narrated that Rasulullah (SAW) said : "Archangel ...
01/12/2025

THE IMPORTANCE OF NEIGHBOUR'S RIGHTS
Aishah and also Abdullah ibn Umar narrated that Rasulullah (SAW) said : "Archangel Jibrael kept on exhorting me about the rights of neighbours until I felt that they would be included in the category of heirs " (Bukhari , Muslim)
Archangel Jibrael was the one who used to bring Allah's revelation to the prophet . So whatever Jibrael said to him concerning neighbours was a revelation from Almighty Allah . It appears from the Hadith the importance of neighbours rights .
And also Abu Hurairah narrated that Rasulullahi (SAW) Said : "He who believe in Allah and the last Day must not put his neighbour to inconvenience , and he who believes in Allah and last Day must speak beneficently or keep quiet "
Abdullah ibn Umar reported that Rasulullah (SAW) Said: "The best companion in the sight of Allah is the one who is the best among all others to his companions, And the best neighbour in the sight of Allah is the one who is the best among all others to his neighbours "
Toju Alabagbe ati Aladugbo Re lai koni wo ti Esin , Eya ati Ede se daada si won ki Olohun le se daada si iwo na . Alfa Ipapo Oloro bi Imoran .

06/11/2025

This is A bitter truth pease listen to it and learn from the bitter truth . Ododo oro bi omo'ya isokuso . Alfa Ipapo Oloro bi Imoran .

31/10/2025

E jeki A gbo'gun ti iwa itoro Baara lawujo Wa. Esin Islam o tako sise Saara (Sodaqo) Sugbon dipo ki A maa fun Alagbe lowo A o se dawon loko owo gege bi aworan toun ti gboloun ti E fe wo yi . Anabi Wa Muhammad ( SAW ) So pe . " E sora kuro nibi mimaa toro , Nitori pe bi won ba fun E won a fi o se yeye bi won o basi tun fun o won a fi o se yeye " Alfa ojogbon kan soro pe . " Titoro lowo Eda (Eniyan) won A maa binu , A e toro lowo Olohun (Allah) inu Re (Olohun ) kii dun " Alfa Ipapo Oloro bi Imoran .

30/10/2025

Awa Obinrin E jeki A daabo bo apole ati iyin ti Olohun fun wa ki A ye fi ihoho Ara wa sile mo . Apeere Obinrin ti o daabo bo ihoho ara Re ati Eleyi ti o si ihoho re sile da gege bi Ogede to pon ti eepo wa lara re ati ogede ti ati bo eepo ara re ti A gbe si ori igba fun tita . Ewo ni awon Eniyan A kowo le fun rira ? Eyi to ni eepo lara ni awon Eniyan A nife si . ki A gbo oro lati enu Eleha yi . Alfa Ipapo oloro bi imoran .

27/10/2025

Huuuuuu. Ododo oro bi omo iya isokuso . Oro ree o , Awa Obinrin E jeki A rati atunbotan ki a A*o daada nipa awon oko wa . Ki a mase gbagbe pe ti ogun ba jelo ogbon nje bo . Nje iwo ara binrin yi tie le se adura pe bi o tise nse si oko Re yi ni ki Aya/ Iyawo omo Re se si omo re Okunrin ? E gbo oro lenu iya yi ki E se atunse ara yin . Alfa IPAPO Oloro bi Imoran .

VISITING THE SICK . "Abu Hurairah narrated that Rasulu Llahi (SAW). Said : When a Muslim visit his brother in sickness ,...
27/10/2025

VISITING THE SICK .
"Abu Hurairah narrated that Rasulu Llahi (SAW). Said : When a Muslim visit his brother in sickness , he certainly continue to pluck fruits of paradise till he return (Muslim) .
" Abu Hurairah reported that Rasulullahi (SAW) said : Allah, The Lord of honour and glory , Will say on the Day of Judgement : Son of Adam ! I was sick and you did not visit Me . The man will exclaim: Lord ! how could I have visited You while you are the lord ot the Worlds . Allah will say : Did you not realize that My servant so and so was sick and you did not visit him . Do you not realize that if you visited him you would have found Me with him .

Address

Lalupon Okuoseju Street Ibadan
Ibadan

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Islamic Sermon posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share