Prophet Peter A K A Ase Tuntun

Prophet Peter A K A Ase Tuntun Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Prophet Peter A K A Ase Tuntun, Ibadan.

25/05/2023

Mo soro gege bi woli olorun wipe oja ti aye fi rin ta ti awon kan fi eku ra bi odun yi se pari lo fun gbogbo okan tori amin se oni' bawon ra ayo ati idun nu ni emi ati gbogbo eyin eniyan yo fi pari odun yi Amin loruko jesu

25/05/2023
25/05/2023

Mo soro Ase jade wipe mo fi omo olorun be ada _eda ati aseda gbogbo igbimo okunkun Lori aye emi ati iwo ina orun tu won ka aye re koja wo inu ogo isinmi re lo lati oni lo

Gbo gbolohun ase oro yi orun damu Samuel ntori dafidi moran ageli yi jade ni tori oro aye re pe ni wonba to okun ki  odu...
22/12/2021

Gbo gbolohun ase oro yi orun damu Samuel ntori dafidi moran ageli yi jade ni tori oro aye re pe ni wonba to okun ki odun yi pari ki olodamu olore alanu re ki odun yi to pari ki o ni eri ayo lorko jesu amin

31/03/2021

Mo soro gege bi woli olorun wipe gbogbo sugbon to ja aye re logun dopin bi osu yi ti pari loni alejo ayo ti aye re bere fun ageli orun dari re si o lati oni lo aye re bo lowo ogun amunisin loruko jesu Amin

IWO ENI TORI AMIN SE NI OLORUN RANMI SI GBO ORO ASE Yi MO SORO GEGE BI WOLI OLORUN  ALAYE WIPE KOTO DI INU OSU KETA FUN ...
27/01/2021

IWO ENI TORI AMIN SE NI OLORUN RANMI SI GBO ORO ASE Yi MO SORO GEGE BI WOLI OLORUN ALAYE WIPE KOTO DI INU OSU KETA FUN OKAN TO FI IGBAGBO SE AMIN ADURA YI KOKORO MOTO YO TO O LOWO WANI ERI AYO NI ORUKO JESU(AMIN)

Address

Ibadan

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Prophet Peter A K A Ase Tuntun posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share