Sacred C&S Light Of God Special Parish

Sacred C&S Light Of God Special Parish Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Sacred C&S Light Of God Special Parish, Religious organisation, Akinlumo, off Bank Olodo, Ibadan.

18/11/2024

Genesis 1:1-3
Fun ibere ojo oni,ibere ose titun yi ati bi odun 2024 42days. Gbogbo juujuu aye re ni Oluwa yio mu kuro. Juujuu lori Omo, lori igbeyawo re ati lori ise re ni Oluwa yio mu kuro. Okunkun inu Aye re yio kuro,Imole yio tan. Bi Oluwa se pase Imole ni ibere dida aye,beni yio pase ki okunkun inu Aye re di Imole. Loni Oluwa yio mu o kuro ninu okunkun, Imule ki Imule ki yio le duro ni iwaju re. Amin

AM USING THIS MEDIUM TO APPRECIATE EVERYONE THAT CONTRIBUTE FOR THE SUCCESS OF THIS YEAR HARVEST. MAY GOD REWARD YOU BACK IN MULTIPLE FOLDS. THANKS.

IN GOD I TRUST

20/06/2023

Oluwa to da imo Antofeli ru,to si ba imo re je,to si poku so,Oluwa ma ba imo awon oludamanran ika je,oro won ko ni se itewogba ma,won yoo fi sesin larin opo eniyan. Bi Oluwa se fi IWO(HOOK) gbe Manase odidi Oba awon to yo e lenu ni Oluwa ma fi se esin,Oluwa ma fi IWO(HOOK)gbe won.
Bi Aja(Dog)se je Jesebeli beni Aja(Dog)ma je awon Aje to gbogun dide si o.
Ota re ma sesin
Alatako re ma te
Niwaju okan ti ati ba o je,iwo ma niyi,iwo ma pada ri Aanu nla gba. Amin.

Iwe Mimo to ko wipe:AYA YO PA ALEJO WON YOO FI IBERU JADE NIBI KOLOFIN WON.!!Alejo gbese ko ni ba o gbe moAlejo aisan ko...
19/06/2023

Iwe Mimo to ko wipe:
AYA YO PA ALEJO WON YOO FI IBERU JADE NIBI KOLOFIN WON.!!
Alejo gbese ko ni ba o gbe mo
Alejo aisan ko ni wo ile re mo
Alejo awon emi airi ni Ina Oluwa ma ti jade.
Awon Alejo ma se rere,Alejo ma ri Aanu gba, Alejo ma ni itesiwaju ni pasan Emi Mimo ma ba.
Baba wa ri Emi Alejo okuta tabi Agbana ti wa ni ori oja re,bi Jesu se fi pasan le won jade ni Tempili,beni o ma le won jade.
Gbogbo emi to ma n tele o tabi saju re de ibi Ogo ni Owo ibinu Oluwa ma le pada.Iwo ma di Ominira ninu ose yi.Amin
Say this:
OSE YI NI OSE IYANU MI FUN ISELOGO.

16/06/2023

Oluwa OLORUN GBAMI LOWO IKU OJIJI,OLORUN OLUGBALA MI IWO LE MI GBOKAN LE.
ISE PU TI EMI YIO SE,NITORI NA DAMI SI.
DAMISI,DAMISI,ISE PO TEMI YOO SE,NITORI RE DAMI SI.

14/06/2023

Oluwa yoo sanu fun o,Oluwa yoo nu gbogbo irekoja re nu kuro,yoo si we o ni awemo.
Iranlowo ni aye re ni lo,lo ri Iranlowo.
Aanu ni ise re ni lo,lo ri Aanu gba
Igbega ni aye re nfe,lori Igbega gba.
Oluwa yoo lo opo eniyan lati gbe o soke,ati lati Sanu fun o.
Beni yoo lo enikan lati yi itan re pada si rere.
Oluwa yoo le awon ota re jina si o,yoo si fi ayika re ati agbegbe re ro e lorun.
Iji gbese yoo dawo duro
Iji Aisan yoo dawo duro
Loni ojo Aanu, Anu nla yoo fohun ninu aye re. AMIN

02/12/2022

Notice and be warned!!.
I CAN SEE SOMEONE IS TRYING TO USED MY MESSENGER PAGE.
Please, I have never ask anybody to there Account details or to tell them I have a platform for quick money.or needs helps for needs.Pls.Dont fall into there victim.Oruko yin ko ni baje oo.But who ever to destroy my name,he or she will never ever no peace.
Oru okan be ma di Ekun fun Iran re.
Ejowo,Esora oooo.

During last Saturday Youth Dinner
07/09/2022

During last Saturday Youth Dinner

Address

Akinlumo, Off Bank Olodo
Ibadan

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Sacred C&S Light Of God Special Parish posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share