Ori oke Fanusetemi ministry

Ori oke Fanusetemi ministry Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Ori oke Fanusetemi ministry, Religious organisation, Badeku, Ibadan.

HAPPY LAST SUNDAY IN NOVEMBER,NINU OSE TITUN YI,E LO RIN NINU ITURA, ANGẸLI TIO KEDE AYO ATI IBUKUN KO BAYIN LALEJO,OTI ...
26/11/2023

HAPPY LAST SUNDAY IN NOVEMBER,NINU OSE TITUN YI,E LO RIN NINU ITURA, ANGẸLI TIO KEDE AYO ATI IBUKUN KO BAYIN LALEJO,OTI RIBE KO UI PADA, JESU KRISTI OLUWA WA....AMIN.....

19/11/2023

HAPPY SUNDAY..*
*NI IWON BA TO KU TI ODUN YII YO FI PARI. AGBARA OLORUN OGA OGO KIO DI YI MU DOPIN.*

*IRANLỌWỌ ỌLỌRUN KIO JÁDE SI AYÉ YIN*

*ẸJẸ JESU KO SAMI ÌYÈ SI YIN LARA TILE TILE*

*JESU OLUWA WA....AMIN.*

31/10/2023

HAPPY LAST DAY OF THE MONTH,OSU TITUN TIE NWO LO LOLA YI,NI ORUKO JESU,ARA ONI NIYIN,BI E TIN WO INU OSU TITUN LO LOLA YIN OWUN TITUN KO BE AYE YIN WO,OUN GBOGBO TI E NILO TI O KAN NINU IRIN AJO AYE YIN,NI ORUKO JESU KRISTI,KIO TE YIN LOWO,NI ORUKO JESU KRISTI OLUWA WA...AMIN...

Reminder 1 day left to go
18/07/2023

Reminder 1 day left to go

Address

Badeku
Ibadan

Telephone

+2347038401142

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ori oke Fanusetemi ministry posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share