YARA IMULE ALYE META

YARA IMULE ALYE META This Wepsite For Only Yoruba People To Enjoin Our Culture Charm To Cure Any Disease In Our Area I Am Comming Back

14/09/2023

Eyi ni phone no.tele pemi si fun iwo to base tan lati mo awon nkan wonyi 09069965885

14/09/2023

Ekurole ninu Ile yi o,asiku asiko yi,mofi asiko yi PE gbogbo Ile yi si akiyesi Lori awon ise ti won post Kiri Lori net PE ka share re kakiri group opolopo re iro lasan ni awon ohun aroriko pelu odi ogun LA ngbe Kiri ori afefe,gege bi opolopo wa semo wipe awon nkan Miran wa ninu awon nkan tafi se ogun ohun toje eewo fun OMO omi ohun ni ogun itusile fun OMO ina elomiran kogbudo je nkan to faya fa melo Lori fise aseje ninu odun yi,to jepe nkan eewo lofi se aseje,ohun lofa ti aye re sifi wa loju kan,ohun lofa to je PE gbogbo osole to nlo koje,koje tete ya ronu re kowa ona abayo Lori lorisirisi awon eewo totilu kodun yi koto bo mo e lowo,,,lati tete wa ona abayo si orisirisi isoro to ndoju kp,eewo totilu ati awon ide toti wonu re,lati wa ona abayo pemi lehin toba fi oruko re oruko IYA re ranse simi ,sora fun awon odi ogun,awon Woli,babalawo,alfa tiwon nlo EMI okunkun lopo kakiri aye loni, won wa eniti won yio fisan eran ajo nihin nimo danu duro,abo oro to fun ologbon eniyan.

18/08/2023
01/08/2023

MOKIWA PE AKU OSUN TUNTUN EMI WA ALAJA .

Send a message to learn more

ose ati ipara osole onfa owo odara lati leje ki ori asiki re lo,koni jeki owo da lowo re,odara fun onisowo,onise owo ,ag...
04/10/2022

ose ati ipara osole onfa owo
odara lati leje ki ori asiki re lo,koni jeki owo da lowo re,odara fun onisowo,onise owo ,agbase se,woli,alfa,onisegun,odara fun awon omo tekateka

13/09/2022

phone no ti wa yato sitiwon gedegbe loyato amato wa yoyin bai kuro 09069965885

13/09/2022

kere ooo mofe pe akiyesi wa si nkankan ninu ile yi
1-mafi owo ranse si alc no kankan,ninu egbe yi,koma ba ko sowo
2- maape phone no.,enikeni ninu egbe yi nitori asiri awon ole kan tu laaro yi tiwon fema fi awon ise kan lu jibiti ninu ile ile amu yin ina omo asi joyin ni odase,ire oo

13/09/2022

ekaro lekan si adura agba ojumore fun gbogbo eyin ololufe temipata nile loko isegun koje temi atiyin,mofe kelo ma kanlekun yara meta yi nibe ni ao tima gba awon pdf awon iwe yen lowo poku,owo idakomu lonjenbe ese monbo

Address

Survlerf
Eko

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when YARA IMULE ALYE META posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share