Whensu Adejoke

Whensu Adejoke To preach the Gospel of God. To remind and tell the people about the second coming of Jesus Christ.

01/11/2025

Osu titun ti a wo loni osu ayo re ni,oro jade ase si tele gbogbo eni ti ona di fun ona ko ma la,eni to nwa iserere ko ma ri gba,iwo to n wa omo gba omo ti re,osu yi osu eri re ni gbogbo eni ti aye npalara o gba itusile anu olorun ko wa ri isegun je ti re a ra o pada a*o e di ominira lati oni lo a ti t**i lae Amin.

29/09/2025

Ara mi olufe nje o mo pe opin ti sun mole,Jesu onipe de mo o,ti Jesu ba de lo ni nibo lo Fe ba Iwo,se Jesu mo e bi,oba yi pada ko gba Jesu loluwa ati olugbala re,fi iwa ese sile iro pipa,agbere sise otimimu oni ruru iwa ipa gbogbo Jesu npe o loni teti si ohun re ao si gba o la, repent from all of your sin and you shall be saved.

29/03/2025

Ni iwon ba to ku ki osu yi pari,mo pase ise rere sinu aye re,anu ti ko lodiwon ko wa eri loruko Jesu be loma ri o ko ma ni yi pada loruko Jesu Amin

01/09/2024

Loruko Jesu ni mo gbadura osu kesan yi a san o sowo,o ma san sire loruko Jesu ase ati aanu to n fare wa fun ni ko ba e rinrin ajo aye re losu yi, loruko Jesu osu yi osu imupadabo sipo re ni

30/07/2024

Gbogbo ire taye ti gba lo lowo re,aseyori re tiwon ti gbese le,orun da won pada fun o loni,wonu ogo tuntun lo eri re ko te o lowo ko gbe gba ope o ti ri be loruko Amin

30/07/2024

Bi osu asepe se npari lo, olorun ko se tire pe,aye re ko ma wa ba kan na mon loruko Jesu

30/07/2024

Aanu wa e ri loruko Jesu

Address

18, Ifelofun Street
Ejigbo

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Whensu Adejoke posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share

Category