21/06/2026
Ori Oro Fun Odun Baba 2026:
'AWON BABA GEGE BI OMOLE FUN IJOBA ORUN"
Bibeli Kika: Heberu 3 : 4, 1 Korinti kinni 3 : 9 - 11.
GEGE BI AWON BABA TI YO JE OMOLE FUN IJOBA ORUN, WON GBODO NI AWON NKAN WON YII...
1. Won gbodo di atunbi.
2. Won gbodo gba Ijoba Olorun laye lati dari won.
3. Won gbodo je Omole, won ko gbodo je baseje
4. Won gbodo le pe se ohun elo fun Idile won.
5. Won gbodo fe Igbe Aye to dara fun Idile won.
6. Won gbodo laya lati le tun awon odi to ti dawo lule se.
7. Won gbodo le fowosowopo pelu Olorun.
8. Won gbodo mo-on-Mo-on gbe Igbe Aye to dara.
9. Won gbodo yago fun Iwa Ipa.
10. Won gbodo le yago fun ohun ti nse Egbe Okunkun.
👉Enikeni ti o ba ni okan lati tele awon nkan won yii ni Omole fun Ijoba Orun, beeni awa Baba gbodo mo wipe ere wa fun Ise Won, ki won si ri wa bi won yoo se gba ere naa, nitori naa, ise wa koni ja si asan, ni Oruko Jesu Kristi. Amin.
Jésu Lolúwa
👉 Preacher:
Rev. Felix Idowu Ajiboye.
👉MMU...
MISSION...
👉MISSION...
MMU
AKU ODUN ooooooo