Sacred C&S youth fellowship, olorun gbebe parish isokan apomu

  • Home
  • Nigeria
  • Apomu
  • Sacred C&S youth fellowship, olorun gbebe parish isokan apomu

Sacred C&S youth fellowship, olorun gbebe parish isokan apomu Prayer points and other Christina activities

Gbo to bari amin nla meta se, apapo owo ogun ti o da owo le iseda ati ogo re, ti o je ki majemu ogo fohun ninu aye re, i...
08/02/2022

Gbo to bari amin nla meta se, apapo owo ogun ti o da owo le iseda ati ogo re, ti o je ki majemu ogo fohun ninu aye re, ina Ori pepe oya ko jo won run

24/11/2021

Iwo egun ati epe ti o wa lori oruko mi, oya eje jesu ko re loni

20/11/2021

Fun iwo iseda eniyan tori amin nla se olori ogun idi ile re, tohun fi iran dajo, oya orun ko lu pa

Gbogbo awon alagbara iñu ebi wa, tio je kinu ri ogo lo, emi oorun oya da won lejo iku loruko jesu
30/09/2021

Gbogbo awon alagbara iñu ebi wa, tio je kinu ri ogo lo, emi oorun oya da won lejo iku loruko jesu

27/09/2021

Mogba ladura, gbogbo alabarin tohun le anu jina sa lodo e, oya orun ko fi ina pin ni ya

23/09/2021

Ogun ajogunba ti mo fi jo baba mi ati iya mi, tohun ko iserere mi, eyin orun e fi ina pin wa ni ya

21/09/2021

Olorun emi awon woli fa oruko emi ati awon omo Jade ninu iwe iranti ogun idile wa.👋👋👋👋

19/09/2021

Mogba ladura gbogbo ogun asoni di ero eyin orun ko ina pin yin ni ya

Address

Barale
Apomu

Telephone

+2347064214467

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Sacred C&S youth fellowship, olorun gbebe parish isokan apomu posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Place Of Worship

Send a message to Sacred C&S youth fellowship, olorun gbebe parish isokan apomu:

Share