Themighty power of god Holy Mountain

Themighty power of god Holy Mountain The Power of the Rock of Salvation Truth

06/06/2022

*C.A.C.orioke mimo agbaranla apata igbala Otito oluwa Labe Agbelebu Jesu Kristi*
Ki agbara ajinde ki o ji ogo re, Ogo Oko re, Ogo iyawo re, Ogo awon Omo re okunrin, Ogo ati awon Omo re Oninrin, Ogo idile yin side, ki e ri Ogo ninu Ogo lo ninu aiye, ki agbara ajinde gbe yin dide kuro ninu oku Ogo ti Iran yin ma wa,
Ogo re, Ogo Oko re, Ogo iyawo re, Ogo awon Omo re okunrin, Ogo awon Omo re Oninrin, Ogo idile yin ko ni wo okunkun, Ogo na ma Tan kagiri Agbaiye
Itanna Ogo re yio tan kagbogbo aiye
Iwo yio je imole Ogo nla fun gbogbo Aiye Iwo ati idile re
*Lati owo Woli Paul ajipejesu* 08141784115

29/12/2021

Ajiboye Adeniyi ayodele Paul Ajipejesu
1. Oluwa, ro ojo ibukun Re sinu aye mi ki n le je ibukun fun awon elomiran.
2. Ran mi lowo Oluwa, lati faraji fun fifun awon iranse Re ninu ohun ti o fi fun mi.
3. Gbadura fun iranlowo ati atileyin atorunwa fun gbogbo awon iranse Olorun ti won je olooto ti won si faraji.
*AFIKUN IBI KIKA FUN ONI: Sekariah 6:9 - 10:2; Ifihan 19:21 - 21:5.*
08141784115 WhatsApp

30/11/2021

IGBEYAWO KI SADEDE FORISANPON; ORISIRSI AWON ISELE NI O WA TI O MAA; YORISI IDOJUDE EYIKEYI IGBEYAWO LEYIN-O-REIN
📖🎂👰🏽‍♂Bi No Olukuluku Oko ati Aya ba Gboran si Oro Olorun Leun ni kikun, Opo Awon Rogbo-Diyan ti o waye ninu awon igbeyawo ode -oni ni ko nii waye; ikosile ati ipinya ko nii maa gba igboro kan
Dida awon Aawo igbeyawo ninu *Aliooto nipa t'isuna-owo
*Ise Asekudorogbo
*Wahala ojoojumo
*awon iwa buburu
*Aidagba-tojuubo
*Adinku ninu imoriri ara-Eni
*Aisi ibasepo Timo-Timo
Igbeyawo je ibasepo laarin Eniyan meeji ti o yato si ara idile won yato baba ati iya won yato iwa won yato gedegede si ra won, Sugbon nigba ti awon mejeeji ti oran na kan ba gbe gege bi alabagbepo ti won ko si maa gbe bii ololufe, a je pe waahaala yio wa ninu idile ti o ba si ife tooto ti won de ara won ti won ma wa asise ara won ogun ati wahaala ma sele ni be

23/11/2021

E Kasan ma

20/10/2021

E Karo ma

Psalms 46:1.,2.,3.,4.,5.,6.,7.,8.,9.,10.,11.1. For the director of music. Of the Sons of Korah. According to alamoth. A ...
06/08/2021

Psalms 46:1.,2.,3.,4.,5.,6.,7.,8.,9.,10.,11.
1. For the director of music. Of the Sons of Korah. According to alamoth. A song. God is our refuge and strength, an ever-present help in trouble.
ỌLỌRUN li àbo wa ati agbara, lọwọlọwọ iranlọwọ ni igba ipọnju. 2. Therefore we will not fear, though the earth give way and the mountains fall into the heart of the sea,
Nitorina li awa kì yio bẹ̀ru, bi a tilẹ ṣi aiye ni idi, ti a si ṣi awọn oke nla nipò lọ si inu okun: 3. though its waters roar and foam and the mountains quake with their surging. Selah
Bi omi rẹ̀ tilẹ nho ti o si nru, bi awọn òke nla tilẹ nmì nipa ọwọ bibì rẹ̀. 4. There is a river whose streams make glad the city of God, the holy place where the Most High dwells.
Odò nla kan wà, ṣiṣan eyiti yio mu inu ilu Ọlọrun dùn, ibi mimọ́ agọ wọnni ti Ọga-ogo. 5. God is within her, she will not fall; God will help her at break of day.
Ọlọrun mbẹ li arin rẹ̀; a kì yio ṣi i ni idi: Ọlọrun yio ràn a lọwọ ni kutukutu owurọ. 6. Nations are in uproar, kingdoms fall; he lifts his voice, the earth melts.
Awọn keferi nbinu, awọn ilẹ ọba ṣidi: o fọhun rẹ̀, aiye yọ́. 7. The LORD Almighty is with us; the God of Jacob is our fortress. Selah
Oluwa awọn ọmọ-ogun wà pẹlu wa; Ọlọrun Jakobu li àbo wa. 8. Come and see the works of the LORD, the desolations he has brought on the earth.
Ẹ wá wò awọn iṣẹ Oluwa, iru ahoro ti o ṣe ni aiye. 9. He makes wars cease to the ends of the earth; he breaks the bow and shatters the spear, he burns the shields with fire.
O mu ọ̀tẹ tan de opin aiye; o ṣẹ́ ọrun, o si ke ọ̀kọ meji; o si fi kẹkẹ́ ogun jona. 10. 'Be still, and know that I am God; I will be exalted among the nations, I will be exalted in the earth.'
Ẹ duro jẹ, ki ẹ si mọ̀ pe emi li Ọlọrun, a o gbé mi ga ninu awọn keferi, a o gbé mi ga li aiye. 11. The LORD Almighty is with us; the God of Jacob is our fortress. Selah
Oluwa awọn ọmọ-ogun wà pẹlu wa; Ọlọrun Jakobu li àbo wa.

22/07/2021

Se Daadaa ni e ji
Oju ayo mo yin
Oju ire mo yin
Ki e ri Oju rare oluwa olorun gba Loni
Ki olorun fi anu wa yin ri
Ki olorun fi anu wa oko re ri
Ki olorun fi anu wa iyawo re ri
Ki olorun fi anu wa awon omo ri okunrun ri
Ki olorun fi anu wa awon omo obinrin ri
Ki a si ma sanu fun idile re

07/07/2021

THE POWER ROCK OF SALVATION TURTH UNDER THE CROSS OF JESUS CHRIST
AGBARA APATA IGBALA OTITO LABE AGBELEBU JESU KRISTI

25/01/2021

Se lku Jesu ko ni ma si asan lori re bayi

24/01/2021

POWERFUL PRAYERS Prayer for peace in the family

God, I thank you and praise you for our family

Help me to dress up with your feelings

where there is hate, let me sow love

where there is pain, forgiveness

where there is doubt, faith

where there is despair, there is hope

where there is darkness, light

where there is sadness, joy

And that everything we do, we do in your name

Amen

Address

Akure

Telephone

+2348141784115

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Themighty power of god Holy Mountain posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Place Of Worship

Send a message to Themighty power of god Holy Mountain:

Share