IPE ODO aguntan ministry

IPE ODO aguntan ministry Mo gbo ipe odo aguntan, Jesu loni ki nwa, ma tele Jesu de opin.

13/02/2022
IGBE AYE KANSOSO,Igbe aye kansoso ko ni pe rekoja 0hun ti a ba se fun Kristi ni yoo pe t**i Ohun aye yi yoo rekoja laipe...
13/01/2022

IGBE AYE KANSOSO,
Igbe aye kansoso ko ni pe rekoja
0hun ti a ba se fun Kristi ni yoo pe t**i
Ohun aye yi yoo rekoja laipe
Sugbon ojo idajo kan nbo
Awon kan lee maa se laalaa fun oro ati owo Sugbon Emi o yan lati sise fun oruko Re
Igbe aye kansoso ,ko ni pe rekoja
Ohun ti a ba se fun kristi ni yoo ta
Adun aye yi fun gba die ni
Laipe a o gba gbogbo re lowo re
Emi yoo lakaka lati se dide si lojojumo
N dun mi wipe igbe-aye kansoso ni mo ni igbe aye kansoso ko ni pe rekoja
Ohun ti a ba se fun Kristi ni yoo pe t**i

06/01/2022

Welcome

Send a message to learn more

Address

Ikorodu
Ajegunle

Telephone

+2349129779541

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when IPE ODO aguntan ministry posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share