Ifá òtúrá orilana temple traditional home's of oracle worshiper

Ifá òtúrá orilana temple traditional home's of oracle worshiper Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Ifá òtúrá orilana temple traditional home's of oracle worshiper, Religious organisation, Afao Ekiti.

31/07/2024

Try dey dey do ifá consultation for every month

.....................OKANRAN-SODE.....................   Pandere-lo-folu-omi-likiti,Ko-iti-romi-awo-ile-olutikun.....awo...
26/07/2024

.....................OKANRAN-SODE..................... Pandere-lo-folu-omi-likiti,Ko-iti-romi-awo-ile-olutikun.....awon lose ifa fun OLUTIKUN EYI TIISE AREMO EWI ADO.....lojo ti n be IFA fun ire gbogbo,lojo tiyio kesi awon AWO re dafa isegun-sete,awon AWO re ye oke-iponri re wo,won ru won so, iyerosun lo kunju opon teetete,Odu nla jade fawo, OKANRAN-SODE laari,won ni ire gbogbo tide,korubo kosi tele ikilo gidi,won ni yio joye ile baba re,aye yoo ye kale,ko kilo fun Aya re kosinfa daada kosi mase biiti AWO,won ni koloma ke IKIN re,ko si rubo ISEGUN,won ni tobaje OBA tan kofi AWO joye AWISE,kole ba pe lori oropo re,won wa ni ti IFA bagbaa beee,kolo marufa pelu(akara-elepo 180,igiripa obuko,eyele funfun 2,obi 9,igba-eru,egun-erunka,otin 2,owo-ifa-totawona............ewe okikan 9,ela,ewe ajeofole,ewe alukerese,ode-ifa,ileke-iyun,ileke-seseefun,abbl...) O gbo ebo nibe o rufa,o wa segun-sete,o di olori,o si tun tele ikilo,ni okan re wabale dale,won wa nsun iyere-ifa bayi wipe (pandere lo folu omi likiti,ko iti romi o omo awo,ifa tobati wa romi tan n o fi iyun dade.........ko iti romi o omo awo) Odu ifa yi kowa leko pupo nipa ODE-IFA lilo siwaju gidi,ami nla gidi ni fun AWO ati idile re tanba re ODE na daada tansi nlo,ibi tasi nlosi po,ise re si po die lara..........Onifa yi ati ile re kanma se geege biifa se nso,ire nlanla yio wole,kogbudo kanju nkankan laye,koteju mon IKIN re,tiko baitini,kolotefa ni kiakia,kotanju Aya re komaba le ire saa nile re,toba ni ifa,kotun mon ifa si gi

II.Ifá pé kí ọmọ Ọ̀ṣẹ́ Ìwòrì tàbí ẹni yòówù tí a dáfá yìí fún dá ẹbọ ọmọ sílẹ̀ dáadáa. Ifá pé kò gbọdọ̀ máa fi ẹbọ ṣe "a...
21/07/2024

II.

Ifá pé kí ọmọ Ọ̀ṣẹ́ Ìwòrì tàbí ẹni yòówù tí a dáfá yìí fún dá ẹbọ ọmọ sílẹ̀ dáadáa. Ifá pé kò gbọdọ̀ máa fi ẹbọ ṣe "alọ́" nítorí ọ̀rọ̀ ọmọ.

Kí eléyìun ó di òpó Ọ̀pẹ̀ mú dáadáa; kó mọ́ ọn "ṣẹbọ ọdún dáadáa nítorí èmi gígùn àti ara líle. If pé púpọ̀ ni ire rẹ̀ láyé.

Ọ̀ṣẹ́ dúdú mo gbejó
Ìwòrì pupa ìdòko
Káb'Ọ̀pẹ̀
Káṣin Ọ̀pẹ̀
Kále gbó kàngẹ́ kàngẹ́

Kọ́mọ ẹni ó lè ba à nàwọ́ gbọ-gbọ-gbọ gbéniṣin
La ṣé ń rúbọ
A dífá fún Bọ̀pẹ̀rúwà
Eléyìí tí ṣe ọmọ bíbí inú Àgbọnnìrègùn
À bọ gbó

À bọ tọ́
À bọ yè
Ọ̀pẹ̀ tẹ́ẹ́rẹ̀ orókè Adó

Ojúmó ire gbogbo lóni

- Ọ̀ṣẹ́ Ìwòrì (Ọ̀ṣẹ́ pa Ìwòrì)

What is Ide Ifa? Ide Ifa is called Otutuopon by Babalawo/IyaAwo, it’s used on the wrist, neck or around waist. Ode Ifa i...
20/07/2024

What is Ide Ifa?

Ide Ifa is called Otutuopon by Babalawo/IyaAwo, it’s used on the wrist, neck or around waist.

Ode Ifa is used as a means of identification, Prestige and most importantly, security! It’s used as a tool to ward off negative spirits from one surroundings.

Before it can perform all these above functions, it must be consecrated. To do that, some people use Eku, Eja, hen, obi, oti, epo, orogbo to consecrate and leave the bead on Ifa for a certain period of time for it to be effective.

When can one receive Otutuopon?

It’s received after Itefa, after receiving One hand of Ifa.

In some cases, their are some Ifa verses that may be revealed maybe during Ifa consultation that will requires that the person that the odu is revealed for needs to receive one Ifa bead as soon as possible maybe for one reason or the other, then such person needs to do that.

When your Otutuopon got broken, it’s advisable that you ask a Yes/No question from Ifa to know if it was a coincidence or a sign.

's

We're active ✔️✔️✔️Work with us
11/03/2024

We're active ✔️✔️✔️
Work with us

20/02/2024
Osalogbe Awo ApalaOsalogbe Awo ApalaaAdifafun Orunmila Ajana Baba Yoofi Oro jagbajagb'a ro Sorun EsuBabagbeboBabaruboEsu...
11/01/2024

Osalogbe Awo Apala
Osalogbe Awo Apalaa
Adifafun Orunmila Ajana
Baba Yoofi Oro jagbajagb'a ro Sorun Esu
Babagbebo
Babarubo
Esu Odara ti n ba Ni Owo lowo Odorun re Esu Odara Odorun re
Esu Odara ti n bani Aya Odorun re Esu Odara Odorun re
Ti n ba bimo
Ti n ba Ko ile
Esuodara ti n ba ni Esin
EsuOdara ti n ba Ni Ire Gbogbo Odorun re
EsuOdara Odorun re

Rudurudukee
Adifafun Orunmila Ajana lojo ti Ire Gbogbo n'lo lojude Edu ti Okookan koyale wa
Babagbebo
Babarubo
Rudurudukee Akara kan Soso Nimoyan fun Esu Ire Aje waa Yale tomi wa o O
Rudurudu Kee Ifakan kii tomi Sol'a
Akara kan Soso Nimoyan f'esu
Ire Aya
Ire Omo
Ire ilekiko
Ire Esin
Ire Alaafia
Akara kan soso nimoyan f'esu Nire Gbogbo Yale tomi wa ooO Rudurudu kee Ifakan kii tomi Sol'a O

Osa Esu✍

Osa n jagbe laja
Awo Baale Difafun Baale won ni kora Ori re legba Nitori Iku
Ogbebo
Orubo
Eetiku ooO
Adesee Akangigiri kii ku ooO
Adesee Akan Gigirii

Igimemu
Igimemu
Igi Alaworo Agutan ni n mondun Memumemu
Adifafun Orunmila Baba Yiowa Igunre mon Esu Odara lorun
EsuOdara darere wa ooO
Dare Sasa darere waa fun Awo 🙏🙏

Osa Esu✍️

ESU ODARA YIOGBEWA O 🙏🙏
🥰🥰🥰🥰🥰❣️

07/01/2024

logbe temple

In      Ifá 💖💖💖We 🤲🤲       Trust 🙏🙏🙏
05/01/2024

In
Ifá 💖💖💖
We 🤲🤲
Trust 🙏🙏🙏

Address

Afao Ekiti

Telephone

+2348144795234

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ifá òtúrá orilana temple traditional home's of oracle worshiper posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Place Of Worship

Send a message to Ifá òtúrá orilana temple traditional home's of oracle worshiper:

Share