18/01/2026
GCC SUNDAY JANUARY 18, 2026 || ALL PRAISE SERVICE
DESCRIPTION
Social Handles Link:
YOUTUBE https://www.youtube.com/channel/UCROFYr2EAmzfHhpD7dnMuBw
FACEBOOK https://web.facebook.com/gracecovenantcentre/videos
SONG PRESENTATION
JESU, E SE O!
Jesu, Jesu, Jesu e se o
(Jesu, Jesu, Jesu e se o)
Alagbara, a gbe o ga
Kabiyesi, a juba re
(Jesu, Jesu, Jesu e se o)
VERSE 1
Gbogbo eniyan ni mo fe ba soro/2x
Ti e l'apa to se gbe, te e l'ese to se e rin o
Te ra fefe rere mi s'inu, te e r'ounje je s'iku o
Te l'alafia o, ati iye Olorun
VERSE 2
Eni n'sokun owo, eni n'ke bosi aya/2x
Iba de'le iwosan ko lo ree r'eemo o
Moni ko gbiyanju, dosipitu lo woran
Lo w'omo eniyan bo ti nfi diro ndiro
Ani lo w'omo eniyan ti kole f'enu jehun mo o
Idi lo fi nbokele, o ma se/2x
VERSE 3
Iwo l'apa to see gbe o, O l'ese to see rin
O o f'apa juwe bee lo o la'ju re lasan
Kilo wa se O o, to le yin Olorun l'ogo/2x
Halleluyah lo ye ko gbenu wa
Ope lo ye ka a f'Edumare
Nitori o, aanu Re duro lailai
Eni ori nfo, lo mo p'aisan kan ko kere
Ani eni eyin ndun o,ni yio mo'yi alafia
VERSE 4
Olorun mi dara, ko seni ti mo le fi we o/2x
Mo l'Olorun to dara, to ngbebi to l'ewa
To n'wuwa to dara, to si n'pero daradara
Olorun mi dara, ko seni ti mo le fi we o/2x
REFRAIN
Ese! Ese! Ese o, ema se (Thank You! Thank You! Oh Thank You!)
Ese, ese o, ema se (Thank You, Thank You, Thank You)