Ifa Eleri Ipin Asoro Dayo

Ifa Eleri Ipin Asoro Dayo 4 ur all problems, barren woman, ladies dat are looking 4 husband,impotent man,quick ej*******on etc

27/04/2026

Mo ki gbogbo eyin Eniyan pe a ku ojo meji meta

27/04/2026

A lo bami Dan ise kekere yii wo,Eye one Kan, ewe ladun ladun (ewe ewuro lo n je be) odindi Ataare Kan, ao jo ao lo kunan ao fi iyo die si, ao maa lo laraaro pelu gbolohun re------akutai awo won lode irodun,osimibakale awo won lode irodun ati nse iru Ori yii si awo won lode okuta, awon ni won file ti oso ti won fehinkule ti Aje ti won nfo kankokango loganjo oru oso ti mo ba se onbe bami be won, Aje ti mo ba se onbe bami be won gbogbo eni ti mo ba se onbe bami be won Tori a kii di ewuro ki o ma dun, a kii di iyo ko ma dun, Eji ogbe Ni baba ifa, Eji ogbe bami gbe ire Aje temi wa

Address

Ase Osi 1 Idiaagba I Lase Road Ado-Ekiti
Ado-Ekiti

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ifa Eleri Ipin Asoro Dayo posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share