The Power of the Rock of Salvation Truth a.k.a Tpotros

The Power of the Rock of Salvation Truth a.k.a Tpotros AGBARA APATA IGBALA LABE AGBELU JESU KRISTI APELE ORI-OKE MIMO AGBARA NLA OLUWA

26/11/2021

E Kasan oooo

11/11/2021

THIS MY MINISTRY
THE MIGHTY POWER OF THE ROCK OF SALVATION TRUTH OF LORD
UNDER THE CROSS OF JSESU CHRIST A.K. A
ORI-OKE MIMO AGBARA NLA APATA IGBALA OTITO OLUWA

28/10/2021

Ki Oluwa Ọlọrun la ọna fún yin

20/10/2021

Mo wa Church ti ma ti se ise iranse ti oluwa olorun gbele lowo
E ku ise oluwa olorun e ni subu Ara beni e ni subu emi sir/ma
Mo Fe iranlowo oluwa olorun lowo yin sir/ma
Mo je omo Bibi ilu ikole Ekiti
Mo si lo si Ile Eko Bible Babajide ni Odun 2003
Mo si se tan ni 28/05/2005
Mo wa Fe iranlowo oluwa olorun lowo won ma mo wa biti ma ti se ise Lori ijo ma
Akure ni mo wa bayi
Ajiyinrere Ajiboye Adeniyi ayodele Paul Ajipejseu
08141784115 / 07069249315
Nigba ti mo wa oju oluwa olorun ninu Adura olorun so fun mi pe ki ma lo si Ibadan Sugbon emi o ni Eniyan si Ibadan o da oruko adugbon na fun mi oluwa olorun ni ki ma lo si Apata ni ilu Ibadan
Gtbank
Account Number 0036299020
Account name ayodele Ajiboye Adeniyi

*IJO APOSTELI TI KRISTI L'AGBAYE.**OMI IYE NAA**OJO ETI (FRIDAY), OCTOBER 15, 2021.**(Ayajo Ojo Awon Obinrin Ti Won Wa N...
15/10/2021

*IJO APOSTELI TI KRISTI L'AGBAYE.*

*OMI IYE NAA*

*OJO ETI (FRIDAY), OCTOBER 15, 2021.*

*(Ayajo Ojo Awon Obinrin Ti Won Wa Ni Igberiko L'agbaye).*

*WA OKUNRIN NAA TI O LE SINMILE.*

*Ka Genesisi 2:21-24*

*AKOSORI: Oluwa Olorun si fi egungun iha ti o mu ni iha okunrin naa mo obinrin, O si mu un to okunrin naa wa (Genesisi 2:22).*

*ITUPALE*
Laiwo ti igbe/ikede awon ajo to n ri si ominira awon obinrin ti o gba ibi gbogbo kan, o je ohun ti ko se e se pe awon obinrin je ohun -elo elege si okunrin. Kii se eesi bi kose ohun ti o ti wa nikale lati seto iru oro yii ni ojo oni tii se Ayajo Ojo Awon Obinrin Ti O Wa Ni Igberiko.
Ni iseda, Olorun yo egungun kan lati iha okunrin to sun oorun ijika naa, pelu re, O da obinrin naa. E je ki a wo o bayii. Niti eniyan, sisakawe okunrin ti a da lati ibere pepe lati inu erupe ile pelu obinrin ti a da lati inu egungun kan lati iha okunrin naa ni ti agbara/okun le ma mogbon wa. Niti eniyan, eto mimu ki egungun iha naa o fe sii, le mu ki eda ti a da nipase re, obinrin naa, o je alailagbara bi okunrin naa. Abajo ti a fi toka si obinrin bi ohun elege *(I Pet. 3:7)*.
Jije alailagbara nipa ti iseda tumosi pe iyawo naa yoo ni lati sinmile agbara okunrin (oko) naa. Bakan naa, o ti di pe Ife iyawo naa yoo maa fa si oko re nikan, eni ti yoo maa je olori/alakoso fun un (3:16). Oun ti o tumo si ni pe gbogbo obinrin nilati wa okunrin kansoso ti Olorun yan, eni ti o le sinmile ni ona ti Olorun.
A ti ri okunrin naa ko le rorun. Arabinrin naa nilo oore-ofe ati ogbon Olorun lati mo arakunrin ti a n soro nipa re yii yato laarin ogooro okunrin to wa laye. Nitori naa o nilo lati wa ni isokan pelu Kristi nipase iyilokan pada, ki Emi Mimo Re o le dari ni ona ti o to *(wo Rom. 8:14)*. Mase yan tabi rin oju ona naa ni ona tire; o lewu lati danikan se e *( wo Owe 16:25)*.

*AWON KOKO ADURA:*
1. Jesu Oluwa, ran mi lowo lati mase se asise ninu awon ohun ti n o maa yan/ipinnu ti n o maase laye.
2. Gbadura fun awon arakunrin/arabinrin ti ko tii laya/loko ni awon ijo wa fun suuru lati duro de Olorun fun eyi to dara julo Re fun won ni ti igbeyawo, idile ati ojo iwaju won.
3. Gbadura pe ki Olorun o fi aanu ati oore-ofe ran awon arakunrin/arabinrin ti won ko tii laya/loko ti won je Kristieni ti won si ti wonu ibadorepo pelu awon afesona ti ko to ati alaiwa-bi-Olorun.

*AFIKUN IBI KIKA FUN ONI: Isaiah 30:14 - 33:14; Filipi 4:17 - 4:23; Kol. 1:1 - 1:15.*

03/10/2021

Iwo ni Ina ope kan, won ba o Dana ope gbogbo eniyan a ba o je onuje Ikomo jade, won ba o je onuje igbeiyawo,won ba o je onuje isile beni gbogbo eniyan ni a ba o je onuje ope pe kuro ni aini ati osi Oju a wa ti ota re asi lo binu pokunso a si ku iku pe o bo
Oruko mi ni woli ajiboye adeniyi ayodele Paul ajipejesu Omo emi mimo
08141784115, 07069249315 Whatsapp number mi ni

30/09/2021

WOLI AYODELE PAUL AJIPEJESU OMO EMI MIMO CONVENER OBINRIN LE NI OWO LOWO JU OKUNKUN SUGBON KI O MA FI SE IGBERAGA SI OKUNKUN NA
: KO DARA KI OKUNRIN MA FI IKAN PAMO FUN AYA RE
O YE KI OKO ATI AYA FI IMO SOKAN NINU IDILE WỌN
O YE KI OKO ATI AYA FI IMO SOKAN NINU IDILE WỌN
KO YE KI OKO ATI AYA MA BA ARA WỌN JA LOJU ÀWỌN OMO TABI LOJU ÀWỌN ENIYAN
KO YE KI OKO ATI AYA MA BA ARA WỌN JA LOJU ÀWỌN OMO TABI LOJU ÀWỌN ENIYAN
KO YE KI OKO ATI AYA MA BA ARA WỌN JA LOJU ÀWỌN OMO TABI LOJU ÀWỌN ENIYAN
O YE KI OKO MA RAN AYA RE LOWO NINU ILE NIPA ISE SISE NINIU ILE
[ O YE KI OKO MA RAN AYA RE LOWO NINU ILE NIPA ISE SISE NINIU ILE
[: O YE KI OKO DA ISE ILÈ DA AYA RE NIKAN O KI KI O MA RANLOWO PELU IFE ISOKAN NINU IDILE WỌN
[ O YE KI OKO DA ISE ILÈ DA AYA RE NIKAN O KI KI O MA RANLOWO PELU IFE ISOKAN NINU IDILE WỌN
[: KO YE KI ÀWỌN OMO MA DA SI ORO TI OKO ATI AYA BASO NINIU ILE LAIPE WỌN SI
[: IWO O GBODO FI AIYE GBA ENIKENI LÁTI DASI ORO IWO ATI AYA RE
[ IWO O GBODO FI AIYE GBA ENIKENI LÁTI DASI ORO IWO ATI OKO RE
BENI MA SE FI ORO OKO RE LO ENIKENI MO
[: IWO O GBODO FI AIYE GBA ENIKENI LÁTI DASI ORO IWO ATI OKO RE
BENI MA SE FI ORO OKO RE LO ENIKENI MO E MA FI ARA DA FUN ARA YIN
NI IFE OKO RE JU ENIKENI LO NI IFE OKO RE JU ÀWỌN OMO RE LO
IFE AYA RE JU ENIKENI LO NI IFE AYA RE JU ÀWỌN OMO RE LO
MA SE JE KI ENIKENI KI O MO OHUN TI O SELE NI ILE YIN
MA FI ORO OKO RE SUN OMO RE MO
MA FI ORO AYA RE SUN ORE MO
ODALE ORE BE BENI OJU LARI OOOO
MA FI OHUNJE OKO FUN OMO SE BENI MA FUN OMO ODO SE FUN RARE SE OKO RE
MA MU INU OKO RE DUN
MA MU INU AYA RE DUN GBOGBO IGBA
MA SE MO TI ARA RE NIKAN

28/09/2021

OLUWA OLORUN A MA MA SE A TI LEYIN YIN PELU IDILE YIN
KI OLORUN RAN ALANU ATI OLORE SI ÀWỌN OMO YIN NA
KI OLORUN MA GBE ENIYAN DIDE FUN IGBE OGO RE
OLORUN MA RAN ALANU ATI OLORE SI YIN NA
OLUWA OLORUN MA GBE OLORE GBE FUN WA OMO RE
E NI DAMU NINU AIYE OMO RE
OMO RE KO NI DAMU NINU AIYE
OGO RE KO NI WO OKUNKUN
OGO OKO RE KONI WO OKUNKUN
OGO AYA RE (YOUR WIFE) KONI WO OKUNKUN
OGO OMO RE KONI WO OKUNKUN BENI KO NI KU
FITILA RE KO NI KU
FITILA AIYE RE KONI KU
OGO IPE RE, OGO ISE IRANSE RE, OGO ISE RE OGO ÀWỌN OMO RE KONI KU BENI KONI WO OKUNKUN
MO FI OLUWA OLORUN BE YIN
MO SI FI OLUWA OLORUN IPE BABALOLA ATI OLUWA OLORUN IPE BABAJIDE BE YIN
MOFI OLUWA OLORUN ALAIYE BE YIN
E NI SE ALAIN NINU AIYE
E JO WO MO NI LO IRANLOWO OLORUN LATI ODO
YIN
MO NILO IRALOWO OLORUN LORI ISE IRANSE MI NI IBADAN
MO LO OWO
BI E SE OLORUN A MA RAN YIN LOWO
E NI SOKUN LORI OKO
E NI SOKUN LORI AYA
E NI SOKUN LORI ÀWỌN OMO
BI E SE DIDE LATI GBE DIDE E NI SUBU
BI E SE KI OWO SA PO LATI FUN OLORUN MA FUN NI IRE RE PADA OWO YIN A MA KUN FUN ORO ATI OLA
BI E SE FE PAMILERIN
E NI SOKUN MO
GTBANK
ACCOUNT NUMBER 0036299020
ACCOUNT NAME AYODELE ADENIYI AJIBOYE

BI O TIWU KI O KO ORO OLA ATI OHUN MIRERE AIYE JO TO BI SE WU KI O NI ORO TOBI O SE WU KI O NI OLA TOBI O SE WU KI O NI ...
26/09/2021

BI O TIWU KI O KO ORO OLA ATI OHUN MIRERE AIYE JO TO
BI SE WU KI O NI ORO TO
BI O SE WU KI O NI OLA TO
BI O SE WU KI O NI OWO TO
BI O SE WU KI O NI ENIYAN
BI O SE WU KI O NI AGBARA TO
BI O SE WU KI AGBARA RE TO
BI O SE WU KI O NI IMO ATI OYE PELU OGBON TO
ASAN NI BENI ASAN NI
FI AIYE RE FUN OLUGBALA RE LONI JESU KRISTI WA O
JESU KRISTI PE O
JESU KRISTI FE RAN RE
FI AIYE RE FUN JESU KRISTI
KI OKU TO DE
WO O BABA, WO O IYA. WO O ARAKUNRIN, WO O ARABINRIN
ASAN NI OFO SI AIYE YI

E ma gbagbe pe awa o fi aiye yi si ni ojo kan
BIBELI MIMỌ ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 1:2-6 Asán ninu asán, bí ọ̀jọ̀gbọ́n ti wí, asán ninu asán, gbogbo rẹ̀ asán ni. Èrè kí ni eniyan ń jẹ ninu gbogbo làálàá rẹ̀, tí ó ń ṣe nílé ayé? Ìran kan ń kọjá lọ, òmíràn ń dé, ṣugbọn ayé wà títí laelae. Oòrùn ń yọ, oòrùn ń wọ̀, ó sì ń yára pada sí ibi tí ó ti yọ wá. Afẹ́fẹ́ ń fẹ́ lọ sí ìhà gúsù, ó sì ń yípo lọ sí ìhà àríwá. Yíyípo ni afẹ́fẹ́ ń yípo, a sì tún pada sí ibi tí ó ti wá.

12/09/2021

IRANSE OLORUN TI EMI ATI MAMA miY NINU OLUWA LO SI ODO RE WIPE O DI GBA TI MO BA NI IYAWO SILE TI O SI BI OMO TABI TI O NI OYUN KI ONA TO LA FUN MI NITORI OHUN TI OLUWA OLORUN fYi HAN WON NI YE
KI NI E FE KI A SE SI ATIPE KI NI ONA ABAYO SI ORO NA BAYI
ORO NA NI MO RO LATI IGBA NA MI O LE SUN BENI MI O LE JEUN LATI IGBA TI IRANSE OLORUN NA TI SO ORO NA 08141784115

THE POWER OF THE ROCK OF SALVATION TRUTH UNDER THE CROSS OF JESUS CHRIST MINISTRYFUN IDILE TI IJOBA OLORUN,OKO RERE ATI ...
08/09/2021

THE POWER OF THE ROCK OF SALVATION TRUTH UNDER THE CROSS OF JESUS CHRIST MINISTRY
FUN IDILE TI IJOBA OLORUN,
OKO RERE ATI AYA RERE NI ILE ATI NINU IJO OLORUN
okunrin ti o ba ri aya rere fe ma ki ye si ona iru okunrin na ma la si wa jusi a si ma se rere
Be si ni Obinrin na ti o ba ri oko rere fe ona Obinrin na a ma la a si ma se rere. Ti e ba si kiyesi won beni omo won na a ma se rere
Olorun le fun aya lowo ju oko lo Sugbon ti o ba je aya rere a si ma fi tanju oko ati omo re a si ma Teriba fun oko re Be si ni Olorun ma fun oko lowo Sugbon ti o ba je oko rere no ma fi tanju aya ati omo re
Proverbs 18:22.
22. He who finds a wife finds what is good and receives favor from the LORD.
Ẹnikẹni ti o ri aya fẹ, o ri ohun rere, o si ri ojurere lọdọ Oluwa.
: Proverbs 12:4.
4. A wife of noble character is her husband's crown, but a disgraceful wife is like decay in his bones.
Obinrin oniwa-rere li ade ọkọ rẹ̀: ṣugbọn eyi ti ndojuti ni dabi ọyún ninu egungun rẹ̀.
: Proverbs 19:14.
14. Houses and wealth are inherited from parents, but a prudent wife is from the LORD.
Ile ati ọrọ̀ li ogún awọn baba: ṣugbọn amoye aya, lati ọdọ Oluwa wá ni.

Ephesians 5:21-33.
21. Submit to one another out of reverence for Christ.
Ẹ mã tẹriba fun ara nyin ni ìbẹru Ọlọrun. 22. Wives, submit to your husbands as to the Lord.
Ẹnyin aya, ẹ mã tẹriba fun awọn ọkọ nyin, gẹgẹ bi fun Oluwa. 23. For the husband is the head of the wife as Christ is the head of the church, his body, of which he is the Savior.
Nitoripe ọkọ ni iṣe ori aya, gẹgẹ bi Kristi ti ṣe ori ijọ enia rẹ̀: on si ni Olugbala ara. 24. Now as the church submits to Christ, so also wives should submit to their husbands in everything.
Nitorina gẹgẹ bi ijọ ti tẹriba fun Kristi, bẹ̃ si ni ki awọn aya ki o mã ṣe si ọkọ wọn li ohun gbogbo. 25. Husbands, love your wives, just as Christ loved the church and gave himself up for her
Ẹnyin ọkọ, ẹ fẹran awọn aya nyin, gẹgẹ bi Kristi si ti fẹran ìjọ, ti o si fi ara rẹ̀ fun u; 26. to make her holy, cleansi

02/09/2021

E Kasan

Address

Akure
Ado-Ekiti

Telephone

+2347069249315

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when The Power of the Rock of Salvation Truth a.k.a Tpotros posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Place Of Worship

Send a message to The Power of the Rock of Salvation Truth a.k.a Tpotros:

Share

Category