22/08/2025
*PRAYER POINTS FOR 22/08/2025 PRAY WITH PSALM 23, ISAIAH 62*
1. LORD, I thank You for upholding me in time of tribulation.
2. I receive the grace to be obedient to the vision of God for my life.
3. I refuse to be afraid, in the name of Jesus.
4. Fire of God, surround me and my children, in the name of Jesus.
5. Every power that is waiting for my unguarded hour to attack me, be destroyed by the fire of God, in the name of Jesus.
6. God of Mercy Rain 2024, settle me, in Jesus’ name.
7. Inside the foundational cage that my stars are kept, come out by fire, in Jesus’ name.
8. Graven image of my father’s house that is supporting evil foundation, in my life be wasted, in Jesus’ name.
9. Pray in the Spirit for 15 minutes.
*KOKO ADURA FUN 22/08/2025 GBADURA PELU ORIN DAFIDI 23, ISAYA 62*
1. OLUWA, modupe l’owo Re fun gbigbe mi ro ni igba idanwo.
2. Mo gba ore-ofe lati se igbonran si iran Olorun fun aiye mi.
3. Mo ko lati beru, ni oruko Jesu.
4. Ina Olorun, yi emi ati awon omo mi ka, ni oruko Jesu.
5. Gbogbo agbara to nduro de akoko aikiyesara mi lati gbogun ti mi, e s’ofo da nu nipa ina Olorun, ni oruko Jesu.
6. Olorun Ojo Aanu 2024, yanju oro mi, l’oruko Jesu.
7. Ninu gbogbo ago ipile ti a de irawo mi mo, ja de pelu ina , ni oruko Jesu.
8. Gbogbo sigidi ile baba mi to nfi owosowopo mo ipile buburu ninu aiye mi, e s’ofo, ni oruko Jesu.
9. Gbadura ninu Emi fun iseju meedogun.