Salaye Anabi Dawah Centre

Salaye Anabi Dawah Centre Informations de contact, plan et itinéraire, formulaire de contact, heures d'ouverture, services, évaluations, photos, vidéos et annonces de Salaye Anabi Dawah Centre, Organisation religieuse, Adjamé.

QURAN39:65) (Tell them clearly that) it was revealed to you and to all Prophets before you: “If you associate any others with Allah in His Divinity, your works will surely come to naught74 and you will certainly be among the losers.”

27/01/2026
30/07/2025
Gbogbo agbenu okunkun se'ka asiri yin koni bo
26/12/2024

Gbogbo agbenu okunkun se'ka asiri yin koni bo

09/10/2024

(masalasi)🤔Ngba owo lati saodi🤷 talo biyin lere ẹjọ? Yoruba pẹlu ẹgan ati ẹtan,kini ilu saodi se funyin náà,bẹẹ sini oore ti saodi nse fún gbogbo agbaye kolo nkan

05/09/2024

Ofo oriburuku original ní nṣe awọn eniyan lọwọlọwọ bayi,eyi tiowa jẹ iyalẹnu ibẹ niwipe awọn alfa nbẹ lara awọn oni sababi àdánwò yi
😥Wal'asir ....🙆🥺🤔😭

30/08/2024
😭😭😭ان العين لتدمع و ان القلب ليحزن و انا على فراقك لمحزونون و لا نقول الا ما يرضي ربنا انا لله و انا اليه راجعونAlfa mi ...
02/07/2024

😭😭😭ان العين لتدمع و ان القلب ليحزن و انا على فراقك لمحزونون و لا نقول الا ما يرضي ربنا انا لله و انا اليه راجعون
Alfa mi buwaeb se otiya naanu 🤔 iku iku kilodeeee😭😭 Olohun bami forijin alfa mi bami ke alfa bami, da alfa mi pọ mọ àwọn ẹni rere Maje ki inú ilé alfa mi o daru léyìn ikú wọn

04/06/2024

Ọdọọdun ni ma n post photo haji 🕋🕌 tiwọn t'ise siwaju lasiko haji, ẹdakun se ẹ fi Renew haji yin ni?, sekarimi tiẹ se lodun tiẹ lọ kotitoyin irọlasan yoruba level

27/05/2024

Jaqmal Fe gba epe lenu awon obinrin🤔 eyin obinrin ẹ lo washing machine lo jare, ko da e le fi for abo to ba wuyin e le fi mop ile ẹle fi fọ asọ ọkọyin ati Iya ati bàbá

Otun kú awọn Olorin ofo yẹn náàAlhamdulillah Ẹseyi dara pupọ aburu ti film nko bawa nilẹ yoruba ọpọ ju daada rẹ lọÀwon f...
23/05/2024

Otun kú awọn Olorin ofo yẹn náà
Alhamdulillah Ẹseyi dara pupọ aburu ti film nko bawa nilẹ yoruba ọpọ ju daada rẹ lọ
Àwon film agbako kan nbẹ lara onti nba nigeria jẹ lowa,ikọkukọ iwokuwo ati isọkusọ tipọ kọjaa bẹ lóde òní, leyi ti aoba lọwọ awọn baba wa tanaa koda aotun ba lọwọ awọn baba tí wọn pilẹ ere ori itage,

Adresse

Adjamé
234

Téléphone

+2250586232235

Site Web

Notifications

Soyez le premier à savoir et laissez-nous vous envoyer un courriel lorsque Salaye Anabi Dawah Centre publie des nouvelles et des promotions. Votre adresse e-mail ne sera pas utilisée à d'autres fins, et vous pouvez vous désabonner à tout moment.

Contacter Le Lieu De Culte

Envoyer un message à Salaye Anabi Dawah Centre:

Partager