03/05/2026
Àbọ́rú Àbọ́yẹ́ Àbọ́ṣíṣe
Ẹsẹ Ifá: Ìrosùn Méjì
O preço da desobediencia
Adífá-fẹ́-pẹ́ ní orúkọ tí a ń pe Ifá,
Aṣẹ̀ṣẹ̀-tẹ̀-nǹkan-ìṣẹ̀m̀báyé-wò ní orúkọ tí a ń pe Ọ̀pẹ̀,
A dífá fún Ọmọ-ẹni-tí-a-pè-kí-ó-rúbọ-tí-kò-rú.
Wọ́n ní kí ó rúbọ kí ó má baà d'ẹni-ìyà,
Wọ́n ní kí ó rúbọ kí ó má baà d'ẹni-ẹ̀gàn.
Kò rú, kò tẹ̀lé ìlànà Awo.
Ó f'etigbọin sí ohùn ẹnu Ẹlẹ́rìí-Ìpín.
Ìgbà tí yóò kòó sí àwọ̀n àwọn Ajogun,
Ó bẹ̀rẹ̀ sí í ké, ó bẹ̀rẹ̀ sí í fohùn ṣọ̀fọ̀.
Ó ní: "Ayé òun d'ojú dé, ire òun d'ẹrù."
Ifá ní: "Ẹni tí a pè kí ó rúbọ, tí kò rú, ìyà mbe fún un."
"Ẹni tí ó gbé'bọ, tí ó rú'bọ, ayé á rọ̀ ọ́."
Ìtúmọ̀/Tradução:
Adífá-fẹ́-pẹ́ (Adivinhar-para-alcançar-longevidade) é o nome de Ifá.
Aṣẹ̀ṣẹ̀-tẹ̀-nǹkan-ìṣẹ̀m̀báyé-wò (é o nome da Palmeira Sagrada (Ọ̀pẹ̀).
Realizaram divinação para o Filho-daquele-que-foi-chamado-para-sacrificar-e-não-o-fez.
Disseram que ele deveria realizar o sacrifício para não sofrer penúria.
Disseram que ele deveria realizar o sacrifício para não sofrer escárnio.
Ele não sacrificou, ele ignorou as instruções do Iniciado (Awo).
Ele fechou os ouvidos para a voz do Testemunho do Destino (Ẹlẹ́rìí-Ìpín).
No momento em que ele caiu na rede dos Ajogun (Guerreiros Destrutivos).
Ele começou a gritar, ele começou a lamentar.
Ele disse: "Minha vida virou de cabeça para baixo, minha sorte tornou-se fardo."
Ifá disse: "Aquele que foi chamado para realizar o sacrifício e não o fez, o sofrimento o aguarda."
"Aquele que aceitou e realizou o sacrifício, a vida lhe será suave."
Ogbó àtọ́ àsúre Ìwòrìwòfún!
Bàbáláwo Ifáṣọlá Ifáṣuyì Ifáfọ́re Èṣùdelé
Ọ̀jẹ̀ Egúngún Àìkúlọlá
Ìjọ Ifá Ọ̀rúnmìlà Ẹ̀gbá Agboọla Oduloju /!!!\ Ilédì Ògbóni Òtúrá Oríkò /!!!\
Kí Ọ̀rúnmìlà má ba wa bùkún sí i
✆ 51 998743787
✆ 51 992300500